diacritcs
stringlengths
1
36.7k
no_diacritcs
stringlengths
1
35.5k
Ìtàn ìgbésí ayé Ábúsálómù , ọmọkùnrin tí Dáfídì Ọba bí ṣèkẹta , jẹ́ àríkọ́gbọ́n fún àwọn tó ń lépa ipò ọlá .
Itan igbesi aye Abusalomu , omokunrin ti Dafidi Oba bi seketa , je arikogbon fun awon to n lepa ipo ola .
Èé ṣe tá ò fi gbọ́dọ̀ tijú láti lọ sọ́dọ̀ àwọn alàgbà fún ìrànlọ́wọ́ láti borí ìwà tó kù díẹ̀ káàtó tá a ń hù ?
Ee se ta o fi gbodo tiju lati lo sodo awon alagba fun iranlowo lati bori iwa to ku die kaato ta a n hu ?
Láti odidi ọdún mẹ́wàá sẹ́yìn báyìí ló ti ń ṣe iṣẹ́ ìsìn alákòókò kíkún .
Lati odidi odun mewaa seyin bayii lo ti n se ise isin alakooko kikun .
Torí náà , ó ṣe pàtàkì pé káwọn tó bá fẹ́ kọra wọn sílẹ̀ ro àròjinlẹ̀ kí wọ́n sì mọ ohun tó lè tẹ̀yìn rẹ̀ yọ kí wọ́n tó ṣe bẹ́ẹ̀ .
Tori naa , o se pataki pe kawon to ba fe kora won sile ro arojinle ki won si mo ohun to le teyin re yo ki won to se bee .
gbogbo ìgbà, dájúdájú wọn kò
gbogbo igba, dajudaju won ko
Lóòótọ́ ni pé àwọn wàhálà kan máa ń bá ìgbà yìí rìn .
Loooto ni pe awon wahala kan maa n ba igba yii rin .
Lẹ́yìn ọjọ́ keje, OLUWA bá mi sọ̀rọ̀, ó ní:
Leyin ojo keje, OLUWA ba mi soro, o ni:
Ó sì kú fún gbogbo wọn kí àwọn tí ó wà láàyè má ṣe tún wà láàyè fún ara wọn mọ́ , bí kò ṣe fún ẹni tí ó kú fún wọn . ” ​ — 2 Kọ́ríńtì 5 : 14 , 15 .
O si ku fun gbogbo won ki awon ti o wa laaye ma se tun wa laaye fun ara won mo , bi ko se fun eni ti o ku fun won . " -- 2 Korinti 5 : 14 , 15 .
Nítorí náà , iṣẹ́ olùṣọ́ àgùntàn táwọn alàgbà ń ṣe kan bíbẹ àwọn ará ìjọ wò lóòrèkóòrè kí wọ́n lè mọ àwọn nǹkan tó ń ṣẹlẹ̀ kí wọ́n sì fún wọn ní ìṣírí látinú ìmọ̀ràn Ìwé Mímọ́ .
Nitori naa , ise oluso aguntan tawon alagba n se kan bibe awon ara ijo wo loorekoore ki won le mo awon nnkan to n sele ki won si fun won ni isiri latinu imoran Iwe Mimo .
Ó yẹ kí àpẹẹrẹ tiwa náà mú kí àwọn míì ní ìgbàgbọ́ nínú Ọlọ́run .
O ye ki apeere tiwa naa mu ki awon mii ni igbagbo ninu Olorun .
Ohun Tó Mú Káwọn Kristẹni Wà Níṣọ̀kan
Ohun To Mu Kawon Kristeni Wa Nisokan
ÀTẸ FÁWẸ́LÌ Ẹ̀KAÈDÈ ÌKÁLẸ̀
ATE FAWELI EKAEDE IKALE
[ Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 19 ]
[ Aworan to wa ni oju iwe 19 ]
Ó tún lè jẹ́ ipò iyì tí Nikodémù wà gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan lára ẹgbẹ́ alákòóso ni kò jẹ́ kó gbé ìgbésẹ̀ pàtàkì ti sísẹ́ ara rẹ̀ .
O tun le je ipo iyi ti Nikodemu wa gege bi okan lara egbe alakooso ni ko je ko gbe igbese pataki ti sise ara re .
bàwo
bawo
Ẹ ò rí i pé ọ̀pọ̀ àǹfààní ló wà nínú kí ìmọ́lẹ̀ Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run máa ṣamọ̀nà wa !
E o ri i pe opo anfaani lo wa ninu ki imole Oro Olorun maa samona wa !
Àbí ńṣe lo máa ń ronú nípa àwọn àtọmọdọ́mọ rẹ̀ , ìyẹn orílẹ̀ - èdè Ísírẹ́lì àtijọ́ ?
Abi nse lo maa n ronu nipa awon atomodomo re , iyen orile - ede Isireli atijo ?
Ẹní bá ṣe panṣágà ń kó ìrora ọkàn bá àwọn ẹlòmíràn kó bàa lè tẹ́ ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn ni , bẹ́ẹ̀ sì rèé , onípanṣágà tí kò ronú pìwà dà ò lè dúró sínú ìfẹ́ Ọlọ́run , nítorí náà yíyọ la ó yọ ọ́ nínú ìjọ Kristẹni mímọ́ .
Eni ba se pansaga n ko irora okan ba awon elomiran ko baa le te ifekufee okan re lorun ni , bee si ree , onipansaga ti ko ronu piwa da o le duro sinu ife Olorun , nitori naa yiyo la o yo o ninu ijo Kristeni mimo .
Ní ti Ọlọrun yìí, pípé ni ọ̀nà rẹ̀,òtítọ́ ni ìlérí OLUWA,ó sì jẹ́ apata fun gbogbo àwọn tí wọ́n bá sápamọ́ sábẹ́ ààbò rẹ̀.
Ni ti Olorun yii, pipe ni ona re,otito ni ileri OLUWA,o si je apata fun gbogbo awon ti won ba sapamo sabe aabo re.
Nítorí náà , ohun mímọ́ tí á ó ti inú rẹ bí , Ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa pè é . ’ — Ìkọ̀wé wínníwínní jẹ́ tiwa ; Lúùkù 1 : 31 - 35 , Bibeli Ajuwe .
Nitori naa , ohun mimo ti a o ti inu re bi , Omo Olorun ni a o maa pe e . ' -- Ikowe winniwinni je tiwa ; Luuku 1 : 31 - 35 , Bibeli Ajuwe .
Mo ṣe ìtọ́jú rẹ ní aginjùní ilẹ̀ tí ó gbẹ tí kò ní omi
Mo se itoju re ni aginjuni ile ti o gbe ti ko ni omi
Àmọ́ , ẹ má jẹ́ kó pẹ́ o .
Amo , e ma je ko pe o .
Àjọ Ìlera Àgbáyé sọ pé lọ́dọọdún , àìjẹunrekánú ń ṣokùnfà ikú tó ń pa àwọn ọmọdé tí iye wọn ju mílíọ̀nù márùn - ún lọ .
Ajo Ilera Agbaye so pe lodoodun , aijeunrekanu n sokunfa iku to n pa awon omode ti iye won ju milionu marun - un lo .
Nítorí náà , Jèhófà Ọlọ́run lẹni tó yẹ ká máa ké pè pé kó ràn wá lọ́wọ́ , kì í ṣe àwọn áńgẹ́lì .
Nitori naa , Jehofa Olorun leni to ye ka maa ke pe pe ko ran wa lowo , ki i se awon angeli .
Ọ̀nà wo ni Ákúílà àti Pírísílà gbà ran Àpólò lọ́wọ́ ?
Ona wo ni Akuila ati Pirisila gba ran Apolo lowo ?
fúnrúngbìn
funrungbin
ìtumọò àwọn ohun tí o kò le ṣe
itumoo awon ohun ti o ko le se
Ète Rere Tá A Fi Ń Sin Ọlọ́run
Ete Rere Ta A Fi N Sin Olorun
Ká sòótọ́ , àwọn ẹ̀dá olóye , ìyẹn èèyàn tàbí áńgẹ́lì tí Ọlọ́run fún ní òmìnira láti ṣe ohun tó wù wọ́n nìkan ló lè ṣe ìpinnu lórí àwọn nǹkan .
Ka sooto , awon eda oloye , iyen eeyan tabi angeli ti Olorun fun ni ominira lati se ohun to wu won nikan lo le se ipinnu lori awon nnkan .
Ìbẹ̀rẹ̀ pípé wo ni ìran ènìyàn ní ?
Ibere pipe wo ni iran eniyan ni ?
Ǹjẹ́ orí rẹ kì í wú tó o bá ka ìròyìn ọdọọdún àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó o sì rí báwọn èèyàn ṣe ń ya wá sínú òtítọ́ jákèjádò ayé ?
Nje ori re ki i wu to o ba ka iroyin odoodun awa Elerii Jehofa to o si ri bawon eeyan se n ya wa sinu otito jakejado aye ?
Dafidi ati àwọn eniyan rẹ̀ sọkún títí tí ó fi rẹ̀ wọ́n.
Dafidi ati awon eniyan re sokun titi ti o fi re won.
Àmọ́ , Mósè ṣì nílò àwọn nǹkan kan kí Jèhófà tó lè gbé iṣẹ́ yẹn fún un .
Amo , Mose si nilo awon nnkan kan ki Jehofa to le gbe ise yen fun un .
Àgbà ni lati ṣe akiyesi àwọn ohun wọnyi ṣọ́ra fún àwọn Òṣèlú nípa ṣi ṣọ́ ìbò ti a di dáradára, owó ni ilé ifowó-pamọ́, wi wo àyíká fún amin ewu ti o le wa ni àyíká, ṣi ṣọ irú ounjẹ ti o yẹ ki a jẹ, àti bẹ́ẹ̀bẹ́ẹ̀ lọ
Agba ni lati se akiyesi awon ohun wonyi sora fun awon Oselu nipa si so ibo ti a di daradara, owo ni ile ifowo-pamo, wi wo ayika fun amin ewu ti o le wa ni ayika, si so iru ounje ti o ye ki a je, ati beebee lo
“Ọwọ́ Serubbabeli ni a ti ṣe ìpìlẹ̀ ilé yìí, ọwọ́ rẹ̀ ni yóò sì parí rẹ̀; ìwọ yóò sì mọ̀ pé, àwọn ọmọ-ogun ni ó rán mi sí i yín.
“Owo Serubbabeli ni a ti se ipile ile yii, owo re ni yoo si pari re; iwo yoo si mo pe, awon omo-ogun ni o ran mi si i yin.
Ó dájú pé ọkọ̀ òkun ńlá tó lágbára lo máa fẹ́ lò nítorí pé á lè la ìgbì òkun lílágbára náà kọjá .
O daju pe oko okun nla to lagbara lo maa fe lo nitori pe a le la igbi okun lilagbara naa koja .
Lẹ́ẹ̀kan yìí kọ oi
Leekan yii ko oi
Báwo lèyí ṣe rí lára ọmọbìnrin Jẹ́fútà ?
Bawo leyi se ri lara omobinrin Jefuta ?
Nípa bẹ́ẹ̀ , àwọn èèyàn gbà pé orúkọ náà , Jèhófà túmọ̀ sí “ Alèwílèṣe . ”
Nipa bee , awon eeyan gba pe oruko naa , Jehofa tumo si " Alewilese . "
Síbẹ̀ , láwọn ìgbà mìíràn nọ́ọ̀sì máa ń ko ìṣòro .
Sibe , lawon igba miiran noosi maa n ko isoro .
Báwo làwọn tó ti ṣègbéyàwó tipẹ́ ṣe lè ran àwọn tí ò tíì pẹ́ tí wọ́n ṣègbéyàwó lọ́wọ́ ?
Bawo lawon to ti segbeyawo tipe se le ran awon ti o tii pe ti won segbeyawo lowo ?
Nírọ̀lẹ́ ọjọ́ Friday kan , mo gbìyànjú láti wí àwíjàre nípa ìdí tí mi ò fi lọ sípàdé fún arákùnrin àti arábìnrin Don àti Dolores Adams , ìyẹn tọkọtaya tí wọ́n ń sìn ní Bẹ́tẹ́lì tí wọ́n sì máa ń gbé mi lọ sípàdé .
Nirole ojo Friday kan , mo gbiyanju lati wi awijare nipa idi ti mi o fi lo sipade fun arakunrin ati arabinrin Don ati Dolores Adams , iyen tokotaya ti won n sin ni Beteli ti won si maa n gbe mi lo sipade .
Lẹ́yìn náà, Joabu fọn fèrè ogun, kí wọ́n dáwọ́ ogun jíjà dúró. Àwọn ọmọ ogun Dafidi bá pada lẹ́yìn àwọn ọmọ ogun Israẹli.
Leyin naa, Joabu fon fere ogun, ki won dawo ogun jija duro. Awon omo ogun Dafidi ba pada leyin awon omo ogun Israeli.
1 , 2 .
1 , 2 .
Kí wá nìdí tí ọ̀pọ̀ ìránṣẹ́ Ọlọ́run tí wọ́n jẹ́ adúróṣinṣin fi ń rí àdánwò àti ìṣòro tó ń mú kí wọ́n wà nínú ìrora àti ìpọ́njú púpọ̀ ?
Ki wa nidi ti opo iranse Olorun ti won je adurosinsin fi n ri adanwo ati isoro to n mu ki won wa ninu irora ati iponju pupo ?
O jẹ olori orilọwọ ti idile ọlọgbọn Szilágyi-Oaş ati Akowe Agba lọwọlọwọ ti Ansamblul Oaşul.[5][6][7] O jẹ ile-iwe giga ti Imọ imọ-ẹrọ ti Cluj-Napoca ati ti University of Babeş-Bolyai.
O je olori orilowo ti idile ologbon Szilagyi-Oas ati Akowe Agba lowolowo ti Ansamblul Oasul.[5][6][7] O je ile-iwe giga ti Imo imo-ero ti Cluj-Napoca ati ti University of Babes-Bolyai.
Bí àwọn tó ń kọ àwọn ìwé wa , àwọn ayàwòrán , àwọn tó ń ṣèwádìí àtàwọn míì bá ti fẹ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ lórí ìwé kan , àwo DVD tàbí ìsọfúnni mìíràn tó dá lórí Bíbélì , wọ́n máa ń lo àwọn ìsọfúnni tó wà ní ìpamọ́ .
Bi awon to n ko awon iwe wa , awon ayaworan , awon to n sewadii atawon mii ba ti fe bere ise lori iwe kan , awo DVD tabi isofunni miiran to da lori Bibeli , won maa n lo awon isofunni to wa ni ipamo .
Ní báyìí , jẹ́ ká ṣàgbéyẹ̀wò bó o ṣe lè kojú àwọn ìṣòro mẹ́ta yìí : ohun tó lè ṣẹlẹ̀ , ohun tó o ronú pé ó ṣẹlẹ̀ àti ohun tó ṣẹlẹ̀ lóòótọ́ .
Ni bayii , je ka sagbeyewo bo o se le koju awon isoro meta yii : ohun to le sele , ohun to o ronu pe o sele ati ohun to sele loooto .
OLUWA sọ pé, “Mo ha gbọdọ̀ fi ohun tí mo fẹ́ ṣe yìí pamọ́ fún Abrahamu,
OLUWA so pe, "Mo ha gbodo fi ohun ti mo fe se yii pamo fun Abrahamu,
Nígbà ti àwọn ọ̀tá Juda ati ti Bẹnjamini gbọ́ pé àwọn tí wọ́n ti ìgbèkùn dé ti bẹ̀rẹ̀ sí kọ́ ilé OLUWA Ọlọrun Israẹli,
Nigba ti awon ota Juda ati ti Benjamini gbo pe awon ti won ti igbekun de ti bere si ko ile OLUWA Olorun Israeli,
Wọ́n máa ń kó jìnnìjìnnì báni , wọ́n sì máa ń rorò gan - an .
Won maa n ko jinnijinni bani , won si maa n roro gan - an .
a sì fi adé kan fún un
a si fi ade kan fun un
Ìtòlẹ́sẹẹsẹ ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì kan náà ni gbogbo ìjọ ń gbádùn jákèjádò ayé .
Itoleseese ikekoo Bibeli kan naa ni gbogbo ijo n gbadun jakejado aye .
Four hundred buffaloes with eight hundred horns, twenty Fulbe men and forty shoes; Ògídíolú did not look back until he had chased Adalo into the bush.
Four hundred buffaloes with eight hundred horns, twenty Fulbe men and forty shoes; Ogidiolu did not look back until he had chased Adalo into the bush.
Báwo sì ni iṣẹ́ ìfigi - ṣe - nǹkan tó kọ́ níbẹ̀rẹ̀ ìgbésí ayé rẹ̀ ṣe ní ipa lórí rẹ̀ nígbà tó yá ?
Bawo si ni ise ifigi - se - nnkan to ko nibere igbesi aye re se ni ipa lori re nigba to ya ?
Nípa èyí , nínú ìwé rẹ̀ , Archaeology of the Land of the Bible — 10,000 − 586 B.C.E . , Amihai Mazar sọ pé : “ Lọ́nà púpọ̀ iṣẹ́ ìwalẹ̀pìtàn . . . jẹ́ iṣẹ́ ọnà , ó sì tún jẹ́ pípa ẹ̀kọ́ pọ̀ mọ́ òye iṣẹ́ .
Nipa eyi , ninu iwe re , Archaeology of the Land of the Bible — 10,000 − 586 B.C.E . , Amihai Mazar so pe : “ Lona pupo ise iwalepitan . . . je ise ona , o si tun je pipa eko po mo oye ise .
Elieseri bí ọmọkunrin kan tí ń jẹ́ Rehabaya, olórí ìdílé rẹ̀, kò sì bí ọmọ mìíràn mọ́, ṣugbọn àwọn ọmọ Rehabaya pọ̀.
Elieseri bi omokunrin kan ti n je Rehabaya, olori idile re, ko si bi omo miiran mo, sugbon awon omo Rehabaya po.
Noga, Nefegi, ati Jafia,
Noga, Nefegi, ati Jafia,
O lo ìwé Sáàmù láti tẹnu mọ́ ọn pé fífi ògo fún Ọlọ́run kan ‘ ìjọsìn , ’ “ ìdúpẹ́ , ” àti “ ìyìn . ” — Sáàmù 95 : 6 ; 100 : 4 , 5 ; 111 : 1 , 2 .
O lo iwe Saamu lati tenu mo on pe fifi ogo fun Olorun kan ' ijosin , ' " idupe , " ati " iyin . " -- Saamu 95 : 6 ; 100 : 4 , 5 ; 111 : 1 , 2 .
Wọ́n sì tún mú ọ̀kànlénígba àwọn òṣìṣẹ́ tẹ́ḿpìlì wá-àwọn ènìyàn tí Dáfídì àti àwọn ìjòyè rẹ gbé kalẹ̀ láti ràn àwọn ọmọ Léfì lọ́wọ́
Won si tun mu okanlenigba awon osise tempili wa-awon eniyan ti Dafidi ati awon ijoye re gbe kale lati ran awon omo Lefi lowo
Àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù tẹnu mọ́ kókó yìí nígbà tó ń sọ̀rọ̀ nípa “ àkópọ̀ ìwà tuntun . ”
Apositeli Poolu tenu mo koko yii nigba to n soro nipa “ akopo iwa tuntun . ”
“ Kò pẹ́ lẹ́yìn èyí , Bryant Gumbel , tó wà ní ilé iṣẹ́ tẹlifíṣọ̀n CBS tẹlifóònù mi láti gbọ́ ohun tí mo rí níbi ìṣẹ̀lẹ̀ ọ̀hún .
" Ko pe leyin eyi , Bryant Gumbel , to wa ni ile ise telifison CBS telifoonu mi lati gbo ohun ti mo ri nibi isele ohun .
Àwọn Àṣàyàn Iṣẹ́
Awon Asayan Ise
Bó o bá fẹ́ ìsọfúnni síwájú sí i tàbí tó o fẹ́ kí ẹnì kan kàn sí ọ nílé láti kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì lọ́fẹ̀ẹ́ , jọ̀wọ́ kọ̀wé sí Jehovah’s Witnesses , P.M.B . 1090 , Benin City 300001 , Edo State , Nigeria , tàbí sí àdírẹ́sì tó bá yẹ lára èyí tí a tò sí ojú ìwé 2 .
Bo o ba fe isofunni siwaju si i tabi to o fe ki eni kan kan si o nile lati ko e lekoo Bibeli lofee , jowo kowe si Jehovah's Witnesses , P.M.B . 1090 , Benin City 300001 , Edo State , Nigeria , tabi si adiresi to ba ye lara eyi ti a to si oju iwe 2 .
Ẹ sì wo bí inú wa ti dùn tó pé a wà lára àwọn tó ń ṣe iṣẹ́ ìkórè tí Ọlọ́run ń darí yìí !
E si wo bi inu wa ti dun to pe a wa lara awon to n se ise ikore ti Olorun n dari yii !
Èyí àtàwọn ẹsẹ míì nínú Bíbélì ṣàlàyé ìdí tí àwọn èèyàn , ìyẹn àwọn ẹni téèyàn kò rò pé wọ́n lè ṣebi fi máa ń ṣe nǹkan tí kò dára tàbí tó burú jáì pàápàá .
Eyi atawon ese mii ninu Bibeli salaye idi ti awon eeyan , iyen awon eni teeyan ko ro pe won le sebi fi maa n se nnkan ti ko dara tabi to buru jai paapaa .
“ ‘Nítorí náà, ẹni tí kò bá kọlà ọkàn ati ti ara ninu àwọn àlejò tí wọn ń gbé ààrin àwọn ọmọ Israẹli kò gbọdọ̀ wọ ibi mímọ́ mi. Èmi OLUWA ni mo sọ bẹ́ẹ̀.’ ”
“ ‘Nitori naa, eni ti ko ba kola okan ati ti ara ninu awon alejo ti won n gbe aarin awon omo Israeli ko gbodo wo ibi mimo mi. Emi OLUWA ni mo so bee.’ ”
Mi ò kì í gbádùn ilé ìwé tí mò ń lọ .
Mi o ki i gbadun ile iwe ti mo n lo .
MAKEDÓNÍÀ
MAKEDONIA
Bí àpẹẹrẹ , ìwádìí tí wọ́n ṣe lẹ́nu àìpẹ́ yìí nípa àwọn ẹlẹ́sìn Kátólíìkì tó wà ní Ítálì fi hàn pé , èèyàn mẹ́fà nínú mẹ́wàá tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ ni kì í lọ jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́ .
Bi apeere , iwadii ti won se lenu aipe yii nipa awon elesin Katoliiki to wa ni Itali fi han pe , eeyan mefa ninu mewaa tabi ju bee lo ni ki i lo jewo ese mo .
Nígbà tí ariwo náà sí rọlẹ̀, Pọ́ọ̀lù ránṣẹ́ pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn, ó sì gbà wọ́n ní ìyànjú, ó dágbére fún wọn, ó dìde láti lọ ṣí Makedóníà
Nigba ti ariwo naa si role, Poolu ranse pe awon omo-eyin, o si gba won ni iyanju, o dagbere fun won, o dide lati lo si Makedonia
Ìtan ohun tó ṣẹlẹ̀ láwọn ilẹ̀ tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn ni orin inú ìwé náà dá lé lórí .
Itan ohun to sele lawon ile ti Bibeli soro nipa won ni orin inu iwe naa da le lori .
Nígbà náà ni kí àwọn tí ń bẹ ní Jùdíà bẹ̀rẹ̀ sí sá lọ sí àwọn òkè ńlá , kí àwọn tí wọ́n sì wà ní àárín rẹ̀ fi ibẹ̀ sílẹ̀ , kí àwọn tí wọ́n sì wà ní àwọn ibi ìgbèríko má ṣe wọ inú rẹ̀ ; nítorí pé ìwọ̀nyí jẹ́ àwọn ọjọ́ fún pípín ìdájọ́ òdodo jáde . ” — Lúùkù 21 : 20 - 22 .
Nigba naa ni ki awon ti n be ni Judia bere si sa lo si awon oke nla , ki awon ti won si wa ni aarin re fi ibe sile , ki awon ti won si wa ni awon ibi igberiko ma se wo inu re ; nitori pe iwonyi je awon ojo fun pipin idajo ododo jade . " -- Luuku 21 : 20 - 22 .
Ó jẹ́ ìfẹ́ tá a gbé karí ìlànà Ọlọ́run .
O je ife ta a gbe kari ilana Olorun .
Akin : Ó dáa , rò ó wò náà : Ká ní a ò mọ orúkọ Mósè , ohun tá a kàn mọ̀ ni pé òun ni ọkùnrin tó pín òkun pupa níyà tó sì tún gba Òfin Mẹ́wàá .
Akin : O daa , ro o wo naa : Ka ni a o mo oruko Mose , ohun ta a kan mo ni pe oun ni okunrin to pin okun pupa niya to si tun gba Ofin Mewaa .
‘ Ẹ̀ṣẹ̀ Wọ Ayé ’
‘ Ese Wo Aye ’
Jésù jẹ́ kó dá àwọn ọmọlẹ́yìn rẹ̀ lójú pé Jèhófà yóò “ fi ẹ̀mí mímọ́ fún àwọn tí ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ . ” — Lúùkù 11 : 13 .
Jesu je ko da awon omoleyin re loju pe Jehofa yoo " fi emi mimo fun awon ti n beere lowo re . " -- Luuku 11 : 13 .
òfin kan pé kí èmi kí ó kọ ọ́ lé orí àwọn àwo wọ̀nyí díẹ̀ nínú àwọn nkan tí mo kãkún pé ó jẹ́ iyebíye jùlọ; pé kí èmi máṣe fi ọwọ́ kàn, àfi ní ṣòkí, nípa ìtàn àwọn ènìyàn yĩ tí à npè ní àwọn ènìyàn Nífáì.
ofin kan pe ki emi ki o ko o le ori awon awo wonyi die ninu awon nkan ti mo kakun pe o je iyebiye julo; pe ki emi mase fi owo kan, afi ni soki, nipa itan awon eniyan yi ti a npe ni awon eniyan Nifai.
78 : 40 - 42 , 52 - 54 ; Neh .
78 : 40 - 42 , 52 - 54 ; Neh .
Gẹ́gẹ́ bí Pọ́ọ̀lù ti ṣàkọsílẹ̀ rẹ̀ , “ Ọba àwọn [ ẹ̀dá èèyàn ] tí ń ṣàkóso gẹ́gẹ́ bí ọba àti Olúwa àwọn [ ẹ̀dá èèyàn ] tí ń ṣàkóso gẹ́gẹ́ bí olúwa ” ni Jésù lóòótọ́ .
Gege bi Poolu ti sakosile re , " Oba awon [ eda eeyan ] ti n sakoso gege bi oba ati Oluwa awon [ eda eeyan ] ti n sakoso gege bi oluwa " ni Jesu loooto .
Bó ti wù kí èdè kan tí a mú rọrùn jẹ́ gbáàtúù tó , òun náà ní ọ̀nà tí wọ́n ń gbà sọ ọ́ .
Bo ti wu ki ede kan ti a mu rorun je gbaatuu to , oun naa ni ona ti won n gba so o .
Bákan náà , nígbà tí “ àwọn aláṣẹ onípò gíga ” bá ní ká má ṣèpàdé mọ́ , a máa ń fọgbọ́n pàdé pọ̀ ní àwùjọ kéékèèké . — Róòmù 13 : 1 ; Héb .
Bakan naa , nigba ti “ awon alase onipo giga ” ba ni ka ma sepade mo , a maa n fogbon pade po ni awujo keekeeke . — Roomu 13 : 1 ; Heb .
Tí kò bá yá ẹ lára láti ṣe bẹ́ẹ̀ , á dáa kó o bi ara ẹ pé , ‘ Kí ló fà á ? ’
Ti ko ba ya e lara lati se bee , a daa ko o bi ara e pe , ‘ Ki lo fa a ? ’
Àwọn kan tó máa ń sọ̀rọ̀ nípa àjọṣe ẹ̀dá sọ pé èrò pé nǹkan ò ní dáa àti àìnítẹ̀ẹ́lọ́rùn wọ́pọ̀ gan - an báyìí .
Awon kan to maa n soro nipa ajose eda so pe ero pe nnkan o ni daa ati ainiteelorun wopo gan - an bayii .
Bẹ́ẹ̀ ni , torí pé ọ̀pọ̀ àǹfààní iṣẹ́ ìsìn ló wà fún wọn báyìí .
Bee ni , tori pe opo anfaani ise isin lo wa fun won bayii .
Òun nìkan ni àpáta ati olùgbàlà mi,òun ni odi mi, a kì yóo tì mí kúrò.
Oun nikan ni apata ati olugbala mi,oun ni odi mi, a ki yoo ti mi kuro.
Ó dájú pé o ò ní gbẹ́kẹ̀ lé e .
O daju pe o o ni gbeke le e .
Lẹ́yìn náà , kó yan àwọn ọkùnrin tó bá kúnjú ìwọ̀n sípò .
Leyin naa , ko yan awon okunrin to ba kunju iwon sipo .
Ọ̀pọ̀ nǹkan ni àwọn olórí ìdílé lè rí kọ́ lára ọkùnrin olóòótọ́ yìí .
Opo nnkan ni awon olori idile le ri ko lara okunrin oloooto yii .
Ó ṣàlàyé pé : “ Èyí tó wù mí jù lọ kí n máa fi kọ́ àwọn ọmọ mi ni Ìwé Ìtàn Bíbélì , ” torí pé “ bí mo ṣe ń kọ́ wọn ni èmi náà ń kẹ́kọ̀ọ́ . ”
O salaye pe : " Eyi to wu mi ju lo ki n maa fi ko awon omo mi ni Iwe Itan Bibeli , " tori pe " bi mo se n ko won ni emi naa n kekoo . "
Jẹ́ ká wo àpẹẹrẹ John , lọ́jọ́ kan , òun àti ìyàwó rẹ̀ jọ fa ọ̀rọ̀ kan , lẹ́yìn náà ó fìbínú gba ilé ọtí lọ .
Je ka wo apeere John , lojo kan , oun ati iyawo re jo fa oro kan , leyin naa o fibinu gba ile oti lo .
Bíbélì sọ fún wa , ó ní : “ Ẹ má gbàgbé rere ṣíṣe àti ṣíṣe àjọpín àwọn nǹkan pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn , irú àwọn nǹkan bẹ́ẹ̀ ni inú Ọlọ́run dùn sí jọjọ . ”
Bibeli so fun wa , o ni : " E ma gbagbe rere sise ati sise ajopin awon nnkan pelu awon elomiran , iru awon nnkan bee ni inu Olorun dun si jojo . "
Bí àpẹẹrẹ , nígbà táwọn míṣọ́nnárì dé sí orílẹ̀ - èdè kan ní Éṣíà níbẹ̀rẹ̀ ọdún 1947 , ọṣẹ́ tí ogun ṣe ṣì nípa lórí orílẹ̀ - èdè náà gan - an lákòókò yẹn , kìkì àwọn ilé díẹ̀ ló sì ní iná mànàmáná .
Bi apeere , nigba tawon misonnari de si orile - ede kan ni Esia nibere odun 1947 , ose ti ogun se si nipa lori orile - ede naa gan - an lakooko yen , kiki awon ile die lo si ni ina manamana .
Báyìí ni ẹ̀yin ṣe jẹ òmùgọ̀ tó bí? Ẹ̀yin tí ó ti bẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé ìgbàgbọ́ yín nípa ti Ẹ̀mí, ṣé a ti wá sọ yín di pípé nípa ti ara ni?
Bayii ni eyin se je omugo to bi? Eyin ti o ti bere igbe aye igbagbo yin nipa ti Emi, se a ti wa so yin di pipe nipa ti ara ni?
Báwo ni nǹkan ṣe wá rí lórílẹ̀ - èdè Cuba báyìí ?
Bawo ni nnkan se wa ri lorile - ede Cuba bayii ?
Ìrètí Tí Wọ́n Bò Mọ́lẹ̀
Ireti Ti Won Bo Mole
Tọmọdé tàgbà ló máa ń láyọ̀ tí wọ́n bá ní àwọn ọ̀rẹ́ gidi tí ìdílé wọn sì fẹ́ràn wọn .
Tomode tagba lo maa n layo ti won ba ni awon ore gidi ti idile won si feran won .
Ọba Ìjọba Ọlọ́run kò ní dá ṣàkóso .
Oba Ijoba Olorun ko ni da sakoso .
KÍ NI gbólóhùn náà “ ọ̀run àpáàdì ” gbé wá sí ọ lọ́kàn ?
KI NI gbolohun naa " orun apaadi " gbe wa si o lokan ?
gbàwẹ̀
gbawe
README.md exists but content is empty.
Downloads last month
37