diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Àmọ́ ṣá o , àwọn nǹkan wọ̀nyí kò túmọ̀ sí pé ìgbéyàwó rẹ ti forí ṣánpọ́n nìyẹn . | Amo sa o , awon nnkan wonyi ko tumo si pe igbeyawo re ti fori sanpon niyen . |
ìjìyà ti jẹ ẹ̀tọ lôrí àwọn aláìgbàgbọ. | ijiya ti je eto lori awon alaigbagbo. |
Àwọn Òǹkàwé Wa Béèrè Pé . . . | Awon Onkawe Wa Beere Pe . . . |
Wọn óo wí pé, “Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí á pada sọ́dọ̀ OLUWA; nítorí bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti fà wá ya, sibẹ yóo wò wá sàn; ó ti pa wá lára lóòótọ́, ṣugbọn yóo di ọgbẹ́ wa. | Won oo wi pe, “E wa, e je ki a pada sodo OLUWA; nitori bi o tile je pe o ti fa wa ya, sibe yoo wo wa san; o ti pa wa lara loooto, sugbon yoo di ogbe wa. |
Nígbà tíyẹn bá wáyé , má ṣe gbà gbé ọ̀rọ̀ tó wà nínú Òwe 24 : 16 , tó sọ pé : “ Olódodo lè ṣubú ní ìgbà méje pàápàá , yóò sì dìde dájúdájú ; ṣùgbọ́n àwọn ẹni burúkú ni a óò mú kọsẹ̀ nípasẹ̀ ìyọnu àjálù . ” | Nigba tiyen ba waye , ma se gba gbe oro to wa ninu Owe 24 : 16 , to so pe : " Olododo le subu ni igba meje paapaa , yoo si dide dajudaju ; sugbon awon eni buruku ni a oo mu kose nipase iyonu ajalu . " |
Júúdà , ọmọ ìyá Jésù mìíràn kọ lẹ́tà onímìísí kan tó fi gba àwọn onígbàgbọ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ níyànjú pé kí wọ́n ja ìjà líle fún ìgbàgbọ́ . | Juuda , omo iya Jesu miiran ko leta onimiisi kan to fi gba awon onigbagbo elegbe re niyanju pe ki won ja ija lile fun igbagbo . |
Wọ́n ní ìfẹ́ni oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ fún ara wọn . | Won ni ifeni onijelenke fun ara won . |
Nínú àwọn ìran Bínúì Ṣíméhì, Ṣélémíáyà, Nátanì, Ádáyà, Mákánádébáì, Ṣásíáì, Ṣáráì, Ásárélì, Ṣélémíáyà, Ṣémáríàyà, Ṣálílúmì, Ámáríyà àti Jóṣẹ́fù | Ninu awon iran Binui Simehi, Selemiaya, Natani, Adaya, Makanadebai, Sasiai, Sarai, Asareli, Selemiaya, Semariaya, Salilumi, Amariya ati Josefu |
Àwọn àjíǹde mẹ́sàn - án yìí mú ká nígbàgbọ́ nínú ohun tí Pọ́ọ̀lù sọ . | Awon ajinde mesan - an yii mu ka nigbagbo ninu ohun ti Poolu so . |
Bí i yẹtí wúrà tàbí ohun ọ̀ṣọ́ ti wúrà dáradára ni ìbáwí ọlọ́gbọ́n fún etí tí ó bá fetísílẹ̀ | Bi i yeti wura tabi ohun oso ti wura daradara ni ibawi ologbon fun eti ti o ba fetisile |
Ashley Callie (ojo ogbon Oṣu kejila ọdun 1976 - ojo karun din logun osu keji odun 2008) jẹ oṣere ara ilu South Africa, ti a mọ julọ fun ipa rẹ gege bi Leone Haines ni Isidingo (2000-08). | Ashley Callie (ojo ogbon Osu kejila odun 1976 - ojo karun din logun osu keji odun 2008) je osere ara ilu South Africa, ti a mo julo fun ipa re gege bi Leone Haines ni Isidingo (2000-08). |
Ní ẹsẹ kìíní , a kà pé : “ Aláyọ̀ ni ẹni tí a dárí ìdìtẹ̀ rẹ̀ jì , tí a bo ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ mọ́lẹ̀ . ” | Ni ese kiini , a ka pe : “ Alayo ni eni ti a dari idite re ji , ti a bo ese re mole . ” |
Nígbà yẹn , Ọlọ́run á ti pa gbogbo àwọn alátakò run . | Nigba yen , Olorun a ti pa gbogbo awon alatako run . |
Ọlọ́run tún “ ṣètò ewéko akèrègbè kan , pé kí ó gòkè wá bo Jónà , kí ó bàa lè di ibòji lórí rẹ̀ , láti dá a nídè kúrò nínú ipò oníyọnu àjálù rẹ̀ . ” | Olorun tun “ seto eweko akeregbe kan , pe ki o goke wa bo Jona , ki o baa le di iboji lori re , lati da a nide kuro ninu ipo oniyonu ajalu re . ” |
Ọ̀rọ̀ OLUWA tí Aisaya sọ ní ọdún tí ọba Ahasi kú: | Oro OLUWA ti Aisaya so ni odun ti oba Ahasi ku: |
máhólì | maholi |
nã sọ fún ìránṣẹ́ rẹ̀, wípé: Jẹ́ kí a lọ sí àwọn ibi ìhà ìsàlẹ̀ ọgbààjàrà nã, kí a sì ṣe àkíyèsí bóyá àwọn ẹ̀ka àdánidá nã ti mú èso búburú jáde pẹ̀lú. | na so fun iranse re, wipe: Je ki a lo si awon ibi iha isale ogbaajara na, ki a si se akiyesi boya awon eka adanida na ti mu eso buburu jade pelu. |
Wọ́n bá wá, wọ́n bẹ̀ wọ́n. Wọ́n sìn wọ́n jáde, wọ́n bá rọ̀ wọ́n pé kí wọ́n kúrò ninu ìlú. | Won ba wa, won be won. Won sin won jade, won ba ro won pe ki won kuro ninu ilu. |
Níbẹ̀rẹ̀ , ó jọ pé orí lásán ló ń fọ́ dádì . | Nibere , o jo pe ori lasan lo n fo dadi . |
Ìlànà nípa Kíkọ Òfin Ọlọrun Sára Òkúta. | Ilana nipa Kiko Ofin Olorun Sara Okuta. |
Kí ni ìbáà ṣẹlẹ̀, tí ẹ fi níláti yára yipada kúrò lọ́dọ̀ OLUWA bẹ́ẹ̀? Bẹ́ẹ̀ sì ni bí ẹ bá ṣe oríkunkun sí OLUWA lónìí, gbogbo àwọn ọmọ Israẹli ni yóo bínú sí lọ́la. | Ki ni ibaa sele, ti e fi nilati yara yipada kuro lodo OLUWA bee? Bee si ni bi e ba se orikunkun si OLUWA lonii, gbogbo awon omo Israeli ni yoo binu si lola. |
Jésù fi dá wa lójú pé Bàbá yóò “ fi ẹ̀mí mímọ́ fún àwọn tí ń béèrè lọ́wọ́ rẹ̀ ! ” | Jesu fi da wa loju pe Baba yoo " fi emi mimo fun awon ti n beere lowo re ! " |
Ó dá Jóòbù lójú pé ó wu Bàbá wa ọ̀run láti jí òun dìde . | O da Joobu loju pe o wu Baba wa orun lati ji oun dide . |
A ò gbé apá mẹ́tẹ̀ẹ̀ta yìí yẹ̀ wò lọ́kọ̀ọ̀kan . | A o gbe apa meteeta yii ye wo lokookan . |
Ó mà ṣe o , ńṣe ló dà bíi pé ó máa ń ṣòro gan - an fáwọn èèyàn láti fi àwọn ohun tó ti ṣẹlẹ̀ kọjá ṣàríkọ́gbọ́n . | O ma se o , nse lo da bii pe o maa n soro gan - an fawon eeyan lati fi awon ohun to ti sele koja sarikogbon . |
Mo kàn ń ṣe ohun tí wọ́n fẹ́ kí n ṣe ni torí kì í ṣe mí bíi pé mo sún mọ́ Ọlọ́run rárá . | Mo kan n se ohun ti won fe ki n se ni tori ki i se mi bii pe mo sun mo Olorun rara . |
Àwọn méjèèjì jọ pohùn pọ̀ pé kò yẹ kí àwọn tún fi àkókò ṣòfò mọ́ , wọ́n sì pinnu láti ràn án lọ́wọ́ nílé . — Wo àpótí náà “ Rírí Ìrànlọ́wọ́ Gbà . ” | Awon mejeeji jo pohun po pe ko ye ki awon tun fi akoko sofo mo , won si pinnu lati ran an lowo nile . -- Wo apoti naa " Riri Iranlowo Gba . " |
Tá a bá ń ṣe bẹ́ẹ̀ , a ò ní dà bí àwọn alágàbàgebè “ tí wọ́n ní ìrísí fífọkànsin Ọlọ́run ṣùgbọ́n tí wọ́n já sí èké ní ti agbára rẹ̀ . ” | Ta a ba n se bee , a o ni da bi awon alagabagebe “ ti won ni irisi fifokansin Olorun sugbon ti won ja si eke ni ti agbara re . ” |
Láìsí àníàní , torí pé bí Jésù Kristi ṣe lo ìgbésí ayé ẹ̀ ṣàrà ọ̀tọ̀ , ó ṣe ọ̀pọ̀ ohun tá a lè kẹ́kọ̀ọ́ lára rẹ̀ . | Laisi aniani , tori pe bi Jesu Kristi se lo igbesi aye e sara oto , o se opo ohun ta a le kekoo lara re . |
Obìnrin opó náà sì dá a lóhùn wí pé, “Bí Ọlọ́run rẹ ti wà, èmi kò ní àkàrà: bí kò ṣe ìkúnwọ́ ìyẹ̀fun nínú ìkòkò àti òróró díẹ̀ nínú kólòbó. Èmi ń ṣa igi díẹ̀ jọ láti kó lọ ilé, kí èmi kí ó sì pèsè rẹ̀ fún mi àti fún ọmọ mi, kí àwa lè jẹ ẹ́: kí a sì kú.” | Obinrin opo naa si da a lohun wi pe, "Bi Olorun re ti wa, emi ko ni akara: bi ko se ikunwo iyefun ninu ikoko ati ororo die ninu kolobo. Emi n sa igi die jo lati ko lo ile, ki emi ki o si pese re fun mi ati fun omo mi, ki awa le je e: ki a si ku." |
yin, wọn yòò borí igba, bí | yin, won yoo bori igba, bi |
nà, bí ò tilẹ̀ jẹ pé ṣíwájú eléyìí ni ẹ | na, bi o tile je pe siwaju eleyii ni e |
Kí sì nìdí tó fi yẹ kó o kíyè sára nígbà tó o bá ń ka àwọn Bíbélì kan ? | Ki si nidi to fi ye ko o kiye sara nigba to o ba n ka awon Bibeli kan ? |
Baaṣa kú, wọ́n sì sin ín sí Tirisa. Ela ọmọ rẹ̀ sì gorí oyè lẹ́yìn rẹ̀. | Baasa ku, won si sin in si Tirisa. Ela omo re si gori oye leyin re. |
Látàrí èyí , kò sí àní - àní pé àwọn jàǹbá oríṣiríṣi tí àṣìṣe ń ṣokùnfà yóò máa bá a lọ láti ṣẹlẹ̀ . | Latari eyi , ko si ani - ani pe awon janba orisirisi ti asise n sokunfa yoo maa ba a lo lati sele . |
Ṣéyẹn wá túmọ̀ sí pé Ọlọ́run ti kádàrá ẹ̀ pé àwọn méjèèjì máa kọ lura wọn ni ? | Seyen wa tumo si pe Olorun ti kadara e pe awon mejeeji maa ko lura won ni ? |
Ìwé Digest tí Olú Ọba Róòmù tó ń jẹ́ Justinian kọ lọ́dún 1468 rèé , ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn ìwé tó sọ̀rọ̀ nípa ọ̀rọ̀ òfin àti ẹjọ́ láyé àtijọ́ | Iwe Digest ti Olu Oba Roomu to n je Justinian ko lodun 1468 ree , o si je okan lara awon iwe to soro nipa oro ofin ati ejo laye atijo |
Èyí ni ètò tí a pinnu rẹ̀ fún gbogbo ayé, èyí ni ọwọ́ tí a nà jáde káàkiri gbogbo orílẹ̀ èdè | Eyi ni eto ti a pinnu re fun gbogbo aye, eyi ni owo ti a na jade kaakiri gbogbo orile ede |
Ìwọ̀nba irú èyí tún ṣẹlẹ̀ láwọn ibi tó léwu , tí ilẹ̀ ti ní ìpele tó ń ri lábẹ́ ara wọn . | Iwonba iru eyi tun sele lawon ibi to lewu , ti ile ti ni ipele to n ri labe ara won . |
▪ Olóde . | # Olode . |
Ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ènìyàn náà dákẹ́ síbẹ̀ wọn kò sì sọ ohunkóhun, láti fi fèsì, nítorí ọba ti paláṣẹ, Ẹ má ṣe dáa lóhùn | Sugbon gbogbo awon eniyan naa dake sibe won ko si so ohunkohun, lati fi fesi, nitori oba ti palase, E ma se daa lohun |
Ṣugbọn OLUWA gba Israẹli là,títí ayé sì ni ìgbàlà rẹ̀.Ojú kò ní tì ọ́, bẹ́ẹ̀ ni o kò ní dààmú, títí lae. | Sugbon OLUWA gba Israeli la,titi aye si ni igbala re.Oju ko ni ti o, bee ni o ko ni daamu, titi lae. |
12 , 13 . ( a ) Àwọn ọ̀nà wo làwọn ìpàdé Kristẹni gbà nílò ìkóra - ẹni - níjàánu ? | 12 , 13 . ( a ) Awon ona wo lawon ipade Kristeni gba nilo ikora - eni - nijaanu ? |
Síbẹ̀ , inú wa dùn láti mọ̀ pé ìgbàgbọ́ wọn dúró digbí lórí ìpìlẹ̀ tó lágbára gan - an . | Sibe , inu wa dun lati mo pe igbagbo won duro digbi lori ipile to lagbara gan - an . |
Ibinu OLUWA ru sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì mú wọn rìn kiri ninu aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún títí gbogbo àwọn tí wọ́n ṣe burúkú níwájú OLUWA fi kú tán. | Ibinu OLUWA ru si awon omo Israeli, o si mu won rin kiri ninu asale fun ogoji odun titi gbogbo awon ti won se buruku niwaju OLUWA fi ku tan. |
Èròjà pàtàkì tí wọ́n fi ń ṣe búrẹ́dì ni ìyẹ̀fun , irú èyí tí wọ́n ń rí lára kóró irúgbìn tí wọ́n gún tàbí tí wọ́n fi ọlọ lọ̀ . | Eroja pataki ti won fi n se buredi ni iyefun , iru eyi ti won n ri lara koro irugbin ti won gun tabi ti won fi olo lo . |
Ẹ̀kẹta , ẹbọ ìràpadà Jésù kò ní jẹ́ kí ẹ̀rí ọkàn máa dá wa lẹ́bi . | Eketa , ebo irapada Jesu ko ni je ki eri okan maa da wa lebi . |
Ǹjẹ́ O Máa Ń Mú Ipò Iwájú Nínú Bíbọlá fún Àwọn Tá A Jọ Jẹ́ Onígbàgbọ́ ? | Nje O Maa N Mu Ipo Iwaju Ninu Bibola fun Awon Ta A Jo Je Onigbagbo ? |
Ọba alágbára, ìwọ tí o fẹ́ràn òdodo,o ti fi ìdí ẹ̀tọ́ múlẹ̀;o ti dá ẹjọ́ ẹ̀tọ́ ati òdodo ní ilẹ̀ Jakọbu. | Oba alagbara, iwo ti o feran ododo,o ti fi idi eto mule;o ti da ejo eto ati ododo ni ile Jakobu. |
‘ Fífẹsẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin ’ túmọ̀ sí pé kéèyàn ‘ dúró digbí síbì kan . ’ | ‘ Fifese mule sinsin ’ tumo si pe keeyan ‘ duro digbi sibi kan . ’ |
Bí àpẹẹrẹ , wọ́n ṣàlàyé pé “ àwọn ọmọ Ọlọ́run ” tó wà nínú Jóòbù 38 : 7 , túmọ̀ sí “ àwùjọ àwọn áńgẹ́lì . ” | Bi apeere , won salaye pe " awon omo Olorun " to wa ninu Joobu 38 : 7 , tumo si " awujo awon angeli . " |
Ọ̀nà pàtàkì wo la lè gbà máa mú ipò iwájú nínú bíbọlá fún gbogbo àwọn tó wà nínú ìjọ ? | Ona pataki wo la le gba maa mu ipo iwaju ninu bibola fun gbogbo awon to wa ninu ijo ? |
Lọ́wọ́ kejì ẹ̀wẹ̀ , Jèhófà máa ń ran àwọn tó bá fi ẹ̀mí ìrònúpìwàdà padà sọ́dọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ . | Lowo keji ewe , Jehofa maa n ran awon to ba fi emi ironupiwada pada sodo re lowo . |
4 Ṣé Ohun Tó Hàn Sí Ojúyòójú Nìkan Lò Ń Rí ? | 4 Se Ohun To Han Si Ojuyooju Nikan Lo N Ri ? |
Àsọyé fún gbogbo ènìyàn tí àkòrí rẹ̀ jẹ́ : “ Ìrísí Ìran Ayé Yìí Ń Yí Padà ” bọ́ sákòókò gan - an ni . | Asoye fun gbogbo eniyan ti akori re je : " Irisi Iran Aye Yii N Yi Pada " bo sakooko gan - an ni . |
KÍ LÈRÒ Ẹ ? | KI LERO E ? |
Oòrùn gbígbóná janjan náà kò kó ìrẹ̀wẹ̀sì bá àwọn olùfọkànsìn arìnrìn - àjò onísìn ti Ìjọ Ọ́tọ́dọ́ọ̀sì ilẹ̀ Gíríìsì tí iye wọ́n ju ẹgbẹ̀rún lọ́nà mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n [ 25,000 ] , tí wọ́n ń tiraka láti dé ibi tí ère ìyá Jésù tí wọ́n ṣe lọ́ṣọ̀ọ́ jìngbìnnì náà wà . | Oorun gbigbona janjan naa ko ko irewesi ba awon olufokansin arinrin - ajo onisin ti Ijo Otodoosi ile Giriisi ti iye won ju egberun lona meeedogbon [ 25,000 ] , ti won n tiraka lati de ibi ti ere iya Jesu ti won se losoo jingbinni naa wa . |
Ọ̀pọ̀ ìgbà ni mo gbàdúrà sí Jèhófà lórí ọ̀rọ̀ yìí . | Opo igba ni mo gbadura si Jehofa lori oro yii . |
14 , 15 . ( a ) Sọ àpẹẹrẹ àwọn tó tún èrò wọn ṣe nípa ojú tí wọ́n fi ń wo àwọn ẹlòmíràn . ( b ) Báwo la ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ wọn ? | 14 , 15 . ( a ) So apeere awon to tun ero won se nipa oju ti won fi n wo awon elomiran . ( b ) Bawo la se le te le apeere won ? |
Níbẹ̀ ni ó wà títí Hẹrọdu fi kú. Èyí rí bẹ́ẹ̀ kí àsọtẹ́lẹ̀ nì lè ṣẹ pé, “Láti Ijipti ni mo ti pe ọmọ mi.” | Nibe ni o wa titi Herodu fi ku. Eyi ri bee ki asotele ni le se pe, “Lati Ijipti ni mo ti pe omo mi.” |
gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ fún àgọ́, àgọ́ àjọ náà | gbogbo ohun oso fun ago, ago ajo naa |
85. Ô dáhùn pé: 'Wọn n tọ ipasẹ̀ | 85. O dahun pe: 'Won n to ipase |
Àmọ́ lọ́jọ́ kan nígbà tí Joel wà lọ́mọ ọdún mẹ́rin , Marc ọmọ wa sọ fún un pé , “ Joel , ó yá , jẹ́ kí Mọ́mì mọ̀ pé o lè ṣe é ! ” | Amo lojo kan nigba ti Joel wa lomo odun merin , Marc omo wa so fun un pe , “ Joel , o ya , je ki Momi mo pe o le se e ! ” |
Ohun tí wọ́n fẹ́ ṣe yìí dára púpọ̀ , àmọ́ Jósẹ́fù ṣì ní láti mọ ohun tó wà lọ́kàn wọn gan - an . | Ohun ti won fe se yii dara pupo , amo Josefu si ni lati mo ohun to wa lokan won gan - an . |
fún oṣù mẹ́ta ” | fun osu meta ” |
Oúnjẹ wòn | Ounje won |
Àwọn ọ̀rẹ́ wa nílé náà ò fi wá sílẹ̀ , wọ́n ń kọ lẹ́tà sí wa lórí kọ̀ǹpútà , wọ́n sì ń fún wa níṣìírí pé ká máa tẹ̀ síwájú . ” — Fílí . | Awon ore wa nile naa o fi wa sile , won n ko leta si wa lori konputa , won si n fun wa nisiiri pe ka maa te siwaju . " -- Fili . |
Jẹ́ kí àwọn ètè irọ́ kí ó dákẹ́ jẹ́ẹ́ pẹ̀lú ìgbéraga àti ìkẹ́gàn | Je ki awon ete iro ki o dake jee pelu igberaga ati ikegan |
Nítorí náà, mo lòdì sí ọ àti sí àwọn odò rẹ, èmi yóò sì mú kí ilẹ̀ Ejibiti di píparun àti ahoro, pátápátá, láti Migdoli lọ dé Siene, dé ààlà ilẹ̀ Kuṣi. | Nitori naa, mo lodi si o ati si awon odo re, emi yoo si mu ki ile Ejibiti di piparun ati ahoro, patapata, lati Migdoli lo de Siene, de aala ile Kusi. |
Má fìgbà kankan gbàgbé àwọn àǹfààní rẹpẹtẹ tó máa ń wá látinú kíka Bíbélì lójoojúmọ́ . | Ma figba kankan gbagbe awon anfaani repete to maa n wa latinu kika Bibeli lojoojumo . |
Kí nìdí tí Sedekáyà fi tètè juwọ́ sílẹ̀ fún àwọn ọmọ aládé àti lẹ́yìn náà fún Ebedi - mélékì ? | Ki nidi ti Sedekaya fi tete juwo sile fun awon omo alade ati leyin naa fun Ebedi - meleki ? |
O lè ka púpọ̀ sí i nínú ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ “ Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé . . . ” nínú ìkànnì wa lórí Íńtánẹ́ẹ̀tì , ìyẹn www.watchtower.org / ype [ Àlàyé ìsàlẹ̀ ìwé ] Orúkọ wọn gan - an kọ́ nìyí . OHUN TÓ YẸ KÓ O RONÚ LÉ LÓRÍ | O le ka pupo si i ninu owo awon apileko “ Awon Odo Beere Pe . . . ” ninu ikanni wa lori Intaneeti , iyen www.watchtower.org / ype [ Alaye isale iwe ] Oruko won gan - an ko niyi . OHUN TO YE KO O RONU LE LORI |
Ẹ jẹ́ ká fi gbogbo ọkàn wa nífẹ̀ẹ́ àwọn ará wa , kí inú wa sì máa dùn sí ìfẹ́ táwọn náà ń fi hàn sí wa . | E je ka fi gbogbo okan wa nifee awon ara wa , ki inu wa si maa dun si ife tawon naa n fi han si wa . |
A máa ń kẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì pa pọ̀ déédéé , àmọ́ Frederick máa ń lo àwọn àkókò yìí láti máa tọ́ka sí àwọn àṣìṣe mi àti bó ṣe yẹ kí n ṣàtúnṣe gẹ́gẹ́ bí aya . | A maa n kekoo Bibeli pa po deedee , amo Frederick maa n lo awon akoko yii lati maa toka si awon asise mi ati bo se ye ki n satunse gege bi aya . |
Kó bàa lè jáwọ́ nínú ohun tó ti di bárakú fún un yìí , ó ṣe ohun kan sórí kọ̀ǹpútà rẹ̀ táá jẹ́ kí kọ̀ǹpútà náà máa kú fúnra rẹ̀ tó bá ti di àkókò tó yẹ kó lọ sùn . — Ka Éfésù 5 : 15 , 16 . | Ko baa le jawo ninu ohun to ti di baraku fun un yii , o se ohun kan sori konputa re taa je ki konputa naa maa ku funra re to ba ti di akoko to ye ko lo sun . -- Ka Efesu 5 : 15 , 16 . |
Olúwa rẹ̀, wípé: Kíni ìdí rẹ̀ tí ìwọ wá sí ibí yĩ láti gbin igi yĩ, tàbí ẹ̀ka igi yĩ? Nítorí kíyèsĩ, ọ̀gangan tí ó ṣá jùlọ nínú gbogbo ilẹ̀ ọgbà-àjàrà rẹ ni. | Oluwa re, wipe: Kini idi re ti iwo wa si ibi yi lati gbin igi yi, tabi eka igi yi? Nitori kiyesi, ogangan ti o sa julo ninu gbogbo ile ogba-ajara re ni. |
A gbé ọ̀rọ̀ náà ka àwọn àpilẹ̀kọ fún ìkẹ́kọ̀ọ́ , èyí tó wà nínú ẹ̀dà Ilé Ìṣọ́ ti oṣù December 15 , 2001 . | A gbe oro naa ka awon apileko fun ikekoo , eyi to wa ninu eda Ile Iso ti osu December 15 , 2001 . |
Bíbélì sọ pé : “ Wọn kò sì fiyè sí i títí ìkún omi fi dé , tí ó sì gbá gbogbo wọn lọ . ” — Mátíù 24 : 39 . | Bibeli so pe : " Won ko si fiye si i titi ikun omi fi de , ti o si gba gbogbo won lo . " -- Matiu 24 : 39 . |
137. Wọn sì ya apá kan sọtọ fún | 137. Won si ya apa kan soto fun |
Báwo la ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́ wọ̀nyí lọ́wọ́ ? | Bawo la se le ran awon odo wonyi lowo ? |
Àbí ẹ ò rí nǹkan , kéèyàn fi ọ̀sẹ̀ méjì rin kìlómítà méjìlélọ́gbọ̀n [ 32 ] péré ! | Abi e o ri nnkan , keeyan fi ose meji rin kilomita mejilelogbon [ 32 ] pere ! |
Èyí ni ọ̀rọ̀ tí àwọn ọmọ-ogun Ọlọ́run Israẹli wí: Ìwọ àti àwọn Ìyàwó rẹ fihàn pẹ̀lú àwọn ìhùwà rẹ àti àwọn ohun tí ó ṣèlérí nígbà tí o wí pé, ‘Àwa yóò mú ẹ̀jẹ́ tí a jẹ́ ṣẹ lórí sísun tùràrí àti dída ẹbọ ohun mímu sí orí ère Ayaba Ọ̀run.’“Tẹ̀síwájú nígbà náà, ṣe ohun tí o sọ, kí o sì mú ẹ̀jẹ́ rẹ ṣẹ. | Eyi ni oro ti awon omo-ogun Olorun Israeli wi: Iwo ati awon Iyawo re fihan pelu awon ihuwa re ati awon ohun ti o seleri nigba ti o wi pe, ‘Awa yoo mu eje ti a je se lori sisun turari ati dida ebo ohun mimu si ori ere Ayaba Orun.’“Tesiwaju nigba naa, se ohun ti o so, ki o si mu eje re se. |
Ṣé Èrò Ọlọ́run Ló Wà Nínú Bíbélì ? | Se Ero Olorun Lo Wa Ninu Bibeli ? |
Lẹ́yìn tí Jésù ké sí Mátíù Léfì , tí í ṣe agbowó orí , pé kí ó wá di ọmọ ẹ̀yìn òun , Léfì filé pọntí , ó fọ̀nà rokà , nítorí Jésù . | Leyin ti Jesu ke si Matiu Lefi , ti i se agbowo ori , pe ki o wa di omo eyin oun , Lefi file ponti , o fona roka , nitori Jesu . |
Ṣùgbọ́n a kò mú àwọn ibi gíga náà kúrò ní Ísírẹ́lì | Sugbon a ko mu awon ibi giga naa kuro ni Isireli |
“ Kò sí ẹni tí ó ní ìfẹ́ tí ó tóbi ju èyí lọ , pé kí ẹnì kan fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ . ” | " Ko si eni ti o ni ife ti o tobi ju eyi lo , pe ki eni kan fi okan re lele nitori awon ore re . " |
Wọ́n tẹ̀ṣíwájú láti lo àwọn ère tí Míkà ṣe, ní gbogbo àkókò tí ilé Ọlọ́run wà ní Ṣílò | Won tesiwaju lati lo awon ere ti Mika se, ni gbogbo akoko ti ile Olorun wa ni Silo |
Ohun mìíràn sì tún ni pé , ó ṣeé ṣe kó ṣì máa dùn ẹ́ , tàbí kó tiẹ̀ máa dùn ẹ́ ju ti tẹ́lẹ̀ lọ . | Ohun miiran si tun ni pe , o see se ko si maa dun e , tabi ko tie maa dun e ju ti tele lo . |
Bó o bá fẹ́ kí tòmátì tètè pọ́n , o lè tò ó sójú fèrèsé níbi tí oòrùn á ti máa ta yẹ́ẹ́ sí i , tàbí kí o kó o sínú abọ́ àdému kan tí ò ní dá ooru púpọ̀ mú un tàbí àpòòwé tó ki tó jẹ́ aláwọ̀ kakí , kó o wá fi tòmátì kan tàbí ọ̀gẹ̀dẹ̀ wẹẹrẹ kan tó ti pọ́n sínú abọ́ tàbí àpòòwé náà . | Bo o ba fe ki tomati tete pon , o le to o soju ferese nibi ti oorun a ti maa ta yee si i , tabi ki o ko o sinu abo ademu kan ti o ni da ooru pupo mu un tabi apoowe to ki to je alawo kaki , ko o wa fi tomati kan tabi ogede weere kan to ti pon sinu abo tabi apoowe naa . |
Pọ́ọ̀lù kọ̀wé sí àwọn Kristẹni bíi tiẹ̀ pé : “ Àwa ní gídígbò kan . . . lòdì sí àwọn olùṣàkóso ayé òkùnkùn yìí , lòdì sí àwọn agbo ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú ní àwọn ibi ọ̀run . ” | Poolu kowe si awon Kristeni bii tie pe : " Awa ni gidigbo kan . . . lodi si awon olusakoso aye okunkun yii , lodi si awon agbo omo ogun emi buruku ni awon ibi orun . " |
Òun nìkanṣoṣo ni ó na ojú ọ̀run lọ, ti ó sì ń rìn lórí ìgbì òkun | Oun nikansoso ni o na oju orun lo, ti o si n rin lori igbi okun |
ṣugbọn ayé, ati ìtànjẹ ọrọ̀, ati ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ mìíràn gba ọkàn wọn, ó sì fún ọ̀rọ̀ náà pa, kò sì so èso. | sugbon aye, ati itanje oro, ati ifekufee miiran gba okan won, o si fun oro naa pa, ko si so eso. |
Ọba Ṣódómù sì wí fún Ábúrámù pé, Kó àwọn ènìyàn mi fún mi, ṣùgbọ́n mú àwọn ẹrù fún ara rẹ | Oba Sodomu si wi fun Aburamu pe, Ko awon eniyan mi fun mi, sugbon mu awon eru fun ara re |
Títukọ̀ Lọ Dójú Ikú | Tituko Lo Doju Iku |
Àwọn Bíbélì míì túmọ̀ apá yìí sí , “ bí ìlà oòrùn ṣe jìnnà sí ìwọ oòrùn . ” | Awon Bibeli mii tumo apa yii si , “ bi ila oorun se jinna si iwo oorun . ” |
Ẹ̀kẹta , ìpàdé ìjọ àti lílọ sí ìpàdé déédéé . | Eketa , ipade ijo ati lilo si ipade deedee . |
sìsẹ́rà | sisera |
Nínú lẹ́tà tí àpọ́sítélì Pọ́ọ̀lù kọ sí àwọn Kristẹni tó jẹ́ Hébérù , ó sọ pé : “ Oúnjẹ líle jẹ́ ti àwọn ènìyàn tí ó dàgbà dénú , ti àwọn tí wọ́n tipasẹ̀ lílò kọ́ [ bíi ti eléré ìdárayá ] agbára ìwòye wọn [ Lóréfèé , “ àwọn ẹ̀yà ara tó ń jẹ́ kéèyàn ní ìmọ̀lára ” ] láti fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tí ó tọ́ àti ohun tí kò tọ́ . ” | Ninu leta ti apositeli Poolu ko si awon Kristeni to je Heberu , o so pe : “ Ounje lile je ti awon eniyan ti o dagba denu , ti awon ti won tipase lilo ko [ bii ti elere idaraya ] agbara iwoye won [ Lorefee , “ awon eya ara to n je keeyan ni imolara ” ] lati fi iyato saaarin ohun ti o to ati ohun ti ko to . ” |
Lákòókò náà , Montano ń bá iṣẹ́ lọ lórí kíka Bíbélì náà àti ṣíṣe àtúnṣe sí i . | Lakooko naa , Montano n ba ise lo lori kika Bibeli naa ati sise atunse si i . |
Ẹ̀yìn ìyẹn ló wá kó lọ sí àgbègbè mìíràn , tí àwọn Ẹlẹ́rìí kò sì mọ ibi tó ń gbé mọ́ . | Eyin iyen lo wa ko lo si agbegbe miiran , ti awon Elerii ko si mo ibi to n gbe mo . |