diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Jahanama ni ibùdésí wọn. O sì jẹ̀ | Jahanama ni ibudesi won. O si je |
Àkọ́bí rẹ̀ lágbára bí akọ mààlúù,Ìwo rẹ̀ sì dàbí ìwo mààlúù tí ó lágbára,tí yóo fi máa ti àwọn orílẹ̀-èdè títí dé òpin ayé.Bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́ ni ẹgbẹẹgbaarun àwọn ọmọ Efuraimu,ati ẹgbẹẹgbẹrun àwọn ọmọ Manase.” | Akobi re lagbara bi ako maaluu,Iwo re si dabi iwo maaluu ti o lagbara,ti yoo fi maa ti awon orile-ede titi de opin aye.Bee gege ni egbeegbaarun awon omo Efuraimu,ati egbeegberun awon omo Manase." |
MÒSÁŃBÍÌKÌ | MOSANBIIKI |
Ọ̀gágun MacArthur mọ ọṣẹ́ ńláǹlà tí bọ́ǹbù átọ́míìkì méjì péré ṣe nígbà tí wọ́n jù wọ́n sí ìlú Nagasaki àti Hiroshima ní ilẹ̀ Japan nígbà tí Ogun Àgbáyé Kejì ń parí lọ . | Ogagun MacArthur mo ose nlanla ti bonbu atomiiki meji pere se nigba ti won ju won si ilu Nagasaki ati Hiroshima ni ile Japan nigba ti Ogun Agbaye Keji n pari lo . |
Lẹ́yìn náà igi yìí di igi ìdáná: Eniyan óo gé ninu rẹ̀, yóo fi dáná yá; yóo gé ninu rẹ̀ yóo fi dáná oúnjẹ; yóo gé ninu rẹ̀, yóo fi gbẹ́ ère, yóo máa bọ ọ́. Eniyan á wá sọ igi lásán tí ó gbẹ́ di oriṣa, á sì máa foríbalẹ̀ fún un. | Leyin naa igi yii di igi idana: Eniyan oo ge ninu re, yoo fi dana ya; yoo ge ninu re yoo fi dana ounje; yoo ge ninu re, yoo fi gbe ere, yoo maa bo o. Eniyan a wa so igi lasan ti o gbe di orisa, a si maa foribale fun un. |
Ọ̀PỌ̀ ọdún lè kọjá kí òjò tó rọ̀ ní aṣálẹ̀ àríwá Chile . | OPO odun le koja ki ojo to ro ni asale ariwa Chile . |
Ní ọdun kìn-ín-ní ijọba rẹ̀, èmi Dáníẹ́lì fi iyè sí i láti inú ìwé, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí wòlíì Jeremáyà, wá pé, àádọ́rin ọdún ni Jérúsálẹ́mù yóò fi wà ní ahoro | Ni odun kin-in-ni ijoba re, emi Danieli fi iye si i lati inu iwe, gege bi oro Oluwa ti wolii Jeremaya, wa pe, aadorin odun ni Jerusalemu yoo fi wa ni ahoro |
Kò sí ohun tá a fẹ́ tí ò sí nínú ìwé náà , ohun tó sì wà níbẹ̀ gan - an làwa olùkọ́ àtàwọn ọ̀dọ́ akẹ́kọ̀ọ́ nílò . ” | Ko si ohun ta a fe ti o si ninu iwe naa , ohun to si wa nibe gan - an lawa oluko atawon odo akekoo nilo . ” |
Èmi yóò sọ àwọn ìlú yín di ahoro, èmi yóò sì ba àwọn ilé mímọ́ yín jẹ́. Èmi kì yóò sì gbọ́ òórùn dídùn yín mọ́. | Emi yoo so awon ilu yin di ahoro, emi yoo si ba awon ile mimo yin je. Emi ki yoo si gbo oorun didun yin mo. |
Lóòótọ́ , ipò àwọn nǹkan nígbà táwọn òbí rẹ àgbà wà léwe lè yàtọ̀ pátápátá sí bó ṣe rí lásìkò tìrẹ . | Loooto , ipo awon nnkan nigba tawon obi re agba wa lewe le yato patapata si bo se ri lasiko tire . |
Nítorí náà , mo dara pọ̀ mọ́ àwọn ọlọ́pàá Moscow tó máa ń kó àwọn tó ń ja ìjà ìgboro , èmi sì ni mò ń kọ́ àwọn ọlọ́pàá bí wọ́n ṣe máa bá àwọn arúfin wọ ìjàkadì . | Nitori naa , mo dara po mo awon olopaa Moscow to maa n ko awon to n ja ija igboro , emi si ni mo n ko awon olopaa bi won se maa ba awon arufin wo ijakadi . |
Láwọn ọ̀ràn mìíràn , ìṣòro náà ni pé ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ ló ní èrò òdì nípa àwọn àgbàlagbà , wọ́n ń fojú ẹni tí kò mọ nǹkan tó ń lọ mọ́ wò wọ́n , pé èrò wọn , ohun tó jẹ́ pàtàkì sí wọn , àtàwọn ohun tí wọ́n nífẹ̀ẹ́ sí kò bá tàwọn mu rárá . | Lawon oran miiran , isoro naa ni pe opo awon odo lo ni ero odi nipa awon agbalagba , won n foju eni ti ko mo nnkan to n lo mo wo won , pe ero won , ohun to je pataki si won , atawon ohun ti won nifee si ko ba tawon mu rara . |
àkọsílẹ̀ yĩ pamọ́ sí Olúwa; àwọn àwo rẹ̀ kò ní iye lórí, nitori àṣẹ Olúwa. Nítorítí o sọ ọ́ nítọ́tọ́ pé ẹnikẹni kò gbọ́dọ̀ ní wọ́n láti ní èrè; ṣùgbọ́n àwọn àkọsílẹ̀ inú rẹ̀ jẹ iyebíye; ẹnikẹ́ni tí ó bá sì sọ ọ́ di mímọ̀, òun ni ẹnití Olúwa yíò bùkún. | akosile yi pamo si Oluwa; awon awo re ko ni iye lori, nitori ase Oluwa. Nitoriti o so o nitoto pe enikeni ko gbodo ni won lati ni ere; sugbon awon akosile inu re je iyebiye; enikeni ti o ba si so o di mimo, oun ni eniti Oluwa yio bukun. |
Apá wo ló yẹ ká fọwọ́ pàtàkì mú nínú ìgbésí ayé wa ? | Apa wo lo ye ka fowo pataki mu ninu igbesi aye wa ? |
Ìwádìí ti fi hàn pé , àwọn iṣẹ́ mẹ́ta pàtàkì táwọn ọlọ́pàá ń ṣe , ìyẹn lílọ káàkiri àwọn òpópónà , yíyára lọ síbi tí ìṣòro pàjáwìrì bá ti ń ṣẹlẹ̀ àti ṣíṣèwádìí lórí ìwà ọ̀daràn , kò lè mú ìwà ọ̀daràn kúrò . | Iwadii ti fi han pe , awon ise meta pataki tawon olopaa n se , iyen lilo kaakiri awon opopona , yiyara lo sibi ti isoro pajawiri ba ti n sele ati sisewadii lori iwa odaran , ko le mu iwa odaran kuro . |
òkùnkùn. pé, 'Kò sí Ọlọrun | okunkun. pe, 'Ko si Olorun |
Ó nígboyà débi pé nígbà tí kìnnìún kan àti béárì kan fẹ́ pa àwọn àgùntàn bàbá rẹ̀ , ó fẹ̀mí ara rẹ̀ wewu láti dáàbò bo àwọn àgùntàn náà . — 1 Sám . | O nigboya debi pe nigba ti kinniun kan ati beari kan fe pa awon aguntan baba re , o femi ara re wewu lati daabo bo awon aguntan naa . — 1 Sam . |
Àjálù Mú Kí N Rí Òtítọ́ | Ajalu Mu Ki N Ri Otito |
kò bá ṣe pé ó na apá rẹ̀ fún ìpamọ́ àwọn bàbá wa, nwọ́n ìbá ti ṣubú sí ọwọ́ àwọn ará Lámánì, nwọ́n ìbá sì ti di ẹni ìpalára sí ìkórira wọn. | ko ba se pe o na apa re fun ipamo awon baba wa, nwon iba ti subu si owo awon ara Lamani, nwon iba si ti di eni ipalara si ikorira won. |
Ọ̀pọ̀ ibi ló ti lòdì sófin láti lo àwọn oògùn kan tàbí kéèyàn ní wọn lọ́wọ́ . | Opo ibi lo ti lodi sofin lati lo awon oogun kan tabi keeyan ni won lowo . |
Ṣọ́ọ̀ṣì Kátólíìkì ló ń bójú tó ọ̀ràn ẹ̀kọ́ . | Soosi Katoliiki lo n boju to oran eko . |
Ọ̀nà wo ló dára jù lọ tá a lè gbà lo Ìwé Mímọ́ tá a bá ń kọ́ àwọn èèyàn lẹ́kọ̀ọ́ ? | Ona wo lo dara ju lo ta a le gba lo Iwe Mimo ta a ba n ko awon eeyan lekoo ? |
Oríṣiríṣi ọ̀nà ni Ọlọ́run gbà bá àwọn tó kọ Bíbélì sọ̀rọ̀ , nígbà míì , ó lè rán áńgẹ́lì sí wọn , ó sì lè bá wọn sọ̀rọ̀ lójú ìran tàbí lójú àlá . | Orisirisi ona ni Olorun gba ba awon to ko Bibeli soro , nigba mii , o le ran angeli si won , o si le ba won soro loju iran tabi loju ala . |
Jesu wọ inú ọkọ̀, ó rékọjá sí òdìkejì òkun, ó bá dé ìlú ara rẹ̀. | Jesu wo inu oko, o rekoja si odikeji okun, o ba de ilu ara re. |
íwọ́ | iwo |
Ṣugbọn pẹlu ìbúra ni, nígbà tí Ọlọrun sọ fún un pé,“Oluwa ti búra,kò ní yí ọ̀rọ̀ rẹ̀ pada:‘Ìwọ máa jẹ́ alufaa títí lae.’ ” | Sugbon pelu ibura ni, nigba ti Olorun so fun un pe,"Oluwa ti bura,ko ni yi oro re pada:'Iwo maa je alufaa titi lae.' " |
àìdi | aidi |
Ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ pé àárín ìlù náà ni Òkè Aboríṣóńṣó - Bìdírẹ̀kẹ̀tẹ̀ ti Oòrùn wà . | O feree je pe aarin ilu naa ni Oke Aborisonso - Bidirekete ti Oorun wa . |
( b ) Kí la máa jíròrò nínú àpilẹ̀kọ yìí ? | ( b ) Ki la maa jiroro ninu apileko yii ? |
Kò sí àní àní, ìyàtọ̀ gbọdọ̀ wa láàrín yín, kí àwọn tí ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà lọ́dọ̀ Ọlọ́run láàrín yín le farahàn kedere. | Ko si ani ani, iyato gbodo wa laarin yin, ki awon ti o se itewogba lodo Olorun laarin yin le farahan kedere. |
Bí wọ́n tiẹ̀ jẹ́ ọ̀dọ́ , wọ́n lè ní ìfọkànbalẹ̀ pé àwọn ọ̀rọ̀ onímìísí yìí kàn àwọn , ọ̀rọ̀ náà sọ pé : “ Máa ṣọ́ aláìlẹ́bi , kí o sì máa wo adúróṣánṣán , nítorí pé ọjọ́ ọ̀la ẹni yẹn yóò kún fún àlàáfíà . ” — Sáàmù 37 : 37 . | Bi won tie je odo , won le ni ifokanbale pe awon oro onimiisi yii kan awon , oro naa so pe : “ Maa so alailebi , ki o si maa wo adurosansan , nitori pe ojo ola eni yen yoo kun fun alaafia . ” — Saamu 37 : 37 . |
Kó o sì tún mọ àǹfààní tí àwọn ọ̀rọ̀ yìí lè ṣe fún wa lónìí àti lọ́jọ́ iwájú . | Ko o si tun mo anfaani ti awon oro yii le se fun wa lonii ati lojo iwaju . |
OLUWA tún bá mi sọ̀rọ̀ ó ní, | OLUWA tun ba mi soro o ni, |
( b ) Àwọn ìbéèrè wo àti orí Bíbélì wo la máa gbé yẹ̀ wò ? | ( b ) Awon ibeere wo ati ori Bibeli wo la maa gbe ye wo ? |
fífẹ́ràn | fiferan |
odidi ọdún mẹ́ta gbako láì | odidi odun meta gbako lai |
Ó ṣe búburú ní ojú , gẹ́gẹ́ bí ilé Ahabu ti ṣe, Nítorí lẹ́yìn ikú baba a rẹ̀, wọ́n di olùgbani nímọ̀ràn rẹ̀ sí ṣíṣe rẹ̀. | O se buburu ni oju , gege bi ile Ahabu ti se, Nitori leyin iku baba a re, won di olugbani nimoran re si sise re. |
Ǹjẹ́ kò yẹ káwa náà máa ronú lórí ìkórè tá a lè rí ní ìpínlẹ̀ ìwàásù wa , dípò ká kàn máa ronú pé aṣálẹ̀ lásán ni ? | Nje ko ye kawa naa maa ronu lori ikore ta a le ri ni ipinle iwaasu wa , dipo ka kan maa ronu pe asale lasan ni ? |
Ṣùgbọ́n èmi yóò dúró ni Efesu títí dí Pentikosti. | Sugbon emi yoo duro ni Efesu titi di Pentikosti. |
Àmọ́ , ojúlówó ìrètí yóò jẹ́ kí ìgbàgbọ́ wa lágbára . | Amo , ojulowo ireti yoo je ki igbagbo wa lagbara . |
Ó sọ pé ńṣe ló dà bíi pé wọ́n ń fẹ́ láti mọ “ ọ̀nà àbùjá ” tí wọ́n á fi lè tètè máa yọrùn kúrò nínú ìṣòro ìdílé kí wọ́n bàa lè gbàgbé nípa rẹ̀ kí wọ́n sì pa dà sídìí iṣẹ́ wọn . | O so pe nse lo da bii pe won n fe lati mo " ona abuja " ti won a fi le tete maa yorun kuro ninu isoro idile ki won baa le gbagbe nipa re ki won si pa da sidii ise won . |
Ohun Tí Bíbélì Sọ Bá Ìmọ̀ Sáyẹ́ǹsì Mu | Ohun Ti Bibeli So Ba Imo Sayensi Mu |
Nígbà tí míṣọ́nnárì kan tó tún jẹ́ atukọ̀ òkun , John Williams débẹ̀ , ó rán àwọn tọkọtaya méjì pé kí wọ́n lọ kọ́ àwọn olùgbé erékùṣù Rarotonga lẹ́kọ̀ọ́ . | Nigba ti misonnari kan to tun je atuko okun , John Williams debe , o ran awon tokotaya meji pe ki won lo ko awon olugbe erekusu Rarotonga lekoo . |
13 , 14 . ( a ) Ìtùnú wo ni àdúrà tí Sólómọ́nì gbà níbi ìyàsímímọ́ tẹ́ńpìlì fún ọ ? | 13 , 14 . ( a ) Itunu wo ni adura ti Solomoni gba nibi iyasimimo tenpili fun o ? |
Mo ronú pé mo máa kú . | Mo ronu pe mo maa ku . |
Àjọ yìí ti tẹ Bíbélì àtàwọn ìwé míì tó dá lórí Bíbélì jáde ní irínwó lé mẹ́tàléláàádọ́rin [ 473 ] èdè . | Ajo yii ti te Bibeli atawon iwe mii to da lori Bibeli jade ni irinwo le metalelaaadorin [ 473 ] ede . |
Ìdí Tó Fi Yẹ Ká Níwà Ọmọlúwàbí | Idi To Fi Ye Ka Niwa Omoluwabi |
Rò ó wò ná , Ọlọ́run tí mo ti ń yán hànhàn láti mọ̀ látìgbà kékeré mi nìyí ! | Ro o wo na , Olorun ti mo ti n yan hanhan lati mo latigba kekere mi niyi ! |
Àmọ́ òmìnira yìí tún ní ìpèníjà tirẹ̀ . | Amo ominira yii tun ni ipenija tire . |
Ní ọjọ́ tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ yóò sọ ẹ̀míi wọn nù nígbà tí ilé ìṣọ́ yóò wó lulẹ̀, odò omi yóò ṣàn lórí òkè gíga àti lórí àwọn òkè kékeré | Ni ojo ti opolopo yoo so emii won nu nigba ti ile iso yoo wo lule, odo omi yoo san lori oke giga ati lori awon oke kekere |
Ó ti wá ṣeé ṣe báyìí láti mú àbùdá láti ara àwọn bakitéríà , fáírọ́ọ̀sì , kòkòrò , ẹran tàbí lára àwọn èèyàn pàápàá kí wọ́n sì fi sínú ohun ọ̀gbìn . ” | O ti wa see se bayii lati mu abuda lati ara awon bakiteria , fairoosi , kokoro , eran tabi lara awon eeyan paapaa ki won si fi sinu ohun ogbin . ” |
Kì í tiẹ̀ fún mi láyè láti sọ̀rọ̀ ! | Ki i tie fun mi laye lati soro ! |
A máa ṣe ìdájọ́ òtítọ́ fún àwọn aláìníbaba ati àwọn opó. Ó fẹ́ràn àwọn àlejò, a sì máa fún wọn ní oúnjẹ ati aṣọ. | A maa se idajo otito fun awon alainibaba ati awon opo. O feran awon alejo, a si maa fun won ni ounje ati aso. |
okè-nla | oke-nla |
Àbí ó ṣàǹfààní kéèyàn jẹ́ ẹlẹ́mìí àlàáfíà ? | Abi o sanfaani keeyan je elemii alaafia ? |
( Ìsẹ 9 : 3 - 6 ) Nígbà tí Pọ́ọ̀lù wà ní Áténì ní Gíríìsì , ó sọ̀rọ̀ nípa “ Ọlọ́run tí ó dá ayé àti gbogbo ohun tí ó wà nínú rẹ̀ . ” | ( Ise 9 : 3 - 6 ) Nigba ti Poolu wa ni Ateni ni Giriisi , o soro nipa “ Olorun ti o da aye ati gbogbo ohun ti o wa ninu re . ” |
Èyí ni Olúwa Ọlọ́run wí | Eyi ni Oluwa Olorun wi |
Ẹ̀mí yìí kì í ṣe Ọlọ́run rárá , ipá ìṣiṣẹ́ tí Ọlọ́run fi máa ń ṣe ohunkóhun tó bá fẹ́ ṣe ni . | Emi yii ki i se Olorun rara , ipa isise ti Olorun fi maa n se ohunkohun to ba fe se ni . |
Ẹsẹ Bíbélì yìí lè jẹ́ kéèyàn mọ̀ pé Bíbélì ni orísun ìtùnú tó yẹ kóun túbọ̀ gbé yẹ̀ wò . | Ese Bibeli yii le je keeyan mo pe Bibeli ni orisun itunu to ye koun tubo gbe ye wo . |
Nítòótọ́ mó ti fi ré ná, nítorí pé, ẹ̀yin kò fi sí ọkàn yín láti bu ọlá fún mi | Nitooto mo ti fi re na, nitori pe, eyin ko fi si okan yin lati bu ola fun mi |
Ṣùgbọ́n jíjẹ́ ọlọ́yàyà àti híhùwà bí ọ̀rẹ́ lè pẹ̀tù sí ohun tí ì bá dá wàhálà sílẹ̀ . | Sugbon jije oloyaya ati hihuwa bi ore le petu si ohun ti i ba da wahala sile . |
Jésù sọ pé : “ A ó sì wàásù ìhìn rere ìjọba yìí ní gbogbo ilẹ̀ ayé tí a ń gbé , láti ṣe ẹ̀rí fún gbogbo àwọn orílẹ̀ - èdè ; nígbà náà ni òpin yóò sì dé . ” — Mátíù 24 : 14 . | Jesu so pe : “ A o si waasu ihin rere ijoba yii ni gbogbo ile aye ti a n gbe , lati se eri fun gbogbo awon orile - ede ; nigba naa ni opin yoo si de . ” — Matiu 24 : 14 . |
Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ náà tí èmi ó fi fún yín | Nigba ti e ba de ile naa ti emi o fi fun yin |
Ninú oríkì ni a ti lè mọ ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀ ẹbí ẹni àti ohun ti a mọ ìdílé mọ́, bí i irú iṣẹ ti wọn nṣe ni ìdílé, oriṣiriṣi èdè ìbílẹ̀ Yorùbá, oúnjẹ ti wọn njẹ àti èyí ti wọn ki i jẹ, ẹ̀sìn ìdílé, àdúgbò ti wọ́n tẹ̀dó si tàbi ìlú ti a ti ṣẹ̀ wá, àṣeyọrí ti wọn ti ṣe ni ìran ẹni àti bẹ́ ẹ̀ bẹ́ ẹ̀ lọ | Ninu oriki ni a ti le mo itan isedale ebi eni ati ohun ti a mo idile mo, bi i iru ise ti won nse ni idile, orisirisi ede ibile Yoruba, ounje ti won nje ati eyi ti won ki i je, esin idile, adugbo ti won tedo si tabi ilu ti a ti se wa, aseyori ti won ti se ni iran eni ati be e be e lo |
Ìfẹ́ Jèhófà àti ti ọmọnìkejì tí wọ́n ní lohun pàtàkì tó jẹ́ kí n lè pa dà sínú agbo Ọlọ́run . ” | Ife Jehofa ati ti omonikeji ti won ni lohun pataki to je ki n le pa da sinu agbo Olorun . " |
Nígbà tí ẹ bá dé ilẹ̀ tí mò ń mu yín lọ, “Bí ẹnìkan bá fẹ́ rú ẹbọ alaafia, tí ó sì mú ẹran láti inú agbo ẹran rẹ̀ fún ẹbọ náà, kì báà jẹ́ akọ tabi abo, ó níláti jẹ́ èyí tí kò ní àbààwọ́n níwájú OLUWA. Nígbà tí yóo bá fi mọ bí a ti í kọ nǹkan burúkú, tí a sì í yan nǹkan rere, wàrà ati oyin ni àwọn eniyan yóo máa jẹ. pé: ta ni ô sọ ẹ̀yí fún ọ?. Òun | Nigba ti e ba de ile ti mo n mu yin lo, “Bi enikan ba fe ru ebo alaafia, ti o si mu eran lati inu agbo eran re fun ebo naa, ki baa je ako tabi abo, o nilati je eyi ti ko ni abaawon niwaju OLUWA. Nigba ti yoo ba fi mo bi a ti i ko nnkan buruku, ti a si i yan nnkan rere, wara ati oyin ni awon eniyan yoo maa je. pe: ta ni o so eyi fun o?. Oun |
Ní gbogbo àsìkò yẹn , ẹ̀gbọ́n mi obìnrin máa ń wá sọ́dọ̀ mi déédéé . | Ni gbogbo asiko yen , egbon mi obinrin maa n wa sodo mi deedee . |
Ńṣe làwọn èèyàn ka ìbálòpọ̀ sí ọ̀nà tí ẹ̀dá lè gbà fi ìfẹ́ni hàn , èyí téèyàn lè ṣe ní ìgbàkígbà tó bá sáà ti wù ú , wọn kò wò ó bí nǹkan tó jẹ́ pé inú ìgbéyàwó nìkan ló gbọ́dọ̀ mọ . | Nse lawon eeyan ka ibalopo si ona ti eda le gba fi ifeni han , eyi teeyan le se ni igbakigba to ba saa ti wu u , won ko wo o bi nnkan to je pe inu igbeyawo nikan lo gbodo mo . |
Bó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n díwọ̀n àwọn eré àṣedárayá “ tí ẹni méjì ń ṣọ́ ara wọn láti pa ara wọn ” nínú rẹ̀ ní ìbámu pẹ̀lú ọjọ́ orí ẹni tó ń ṣe eré náà , òtítọ́ ibẹ̀ ni pé wọn kì í fi bẹ́ẹ̀ lè ṣàkóso wọn . | Bo tile je pe won diwon awon ere asedaraya " ti eni meji n so ara won lati pa ara won " ninu re ni ibamu pelu ojo ori eni to n se ere naa , otito ibe ni pe won ki i fi bee le sakoso won . |
Bákan náà ló ṣe yẹ kó o fẹ́ láti kẹ́kọ̀ọ́ lára Kristi kó o sì máa tẹ̀ lé àpẹẹrẹ rẹ̀ . | Bakan naa lo se ye ko o fe lati kekoo lara Kristi ko o si maa te le apeere re . |
Ǹjẹ́ ò ń sapá láti jèrè ìmọ̀ pípéye yẹn ? | Nje o n sapa lati jere imo pipeye yen ? |
Bíbélì sọ pé èèyàn tó bá ń gbé irú ìgbé ayé bẹ́ẹ̀ , á “ dà bí igi tí a gbìn sẹ́bàá àwọn ìṣàn omi , tí ń pèsè èso tirẹ̀ ní àsìkò rẹ̀ èyí tí àwọn ẹ̀ka rẹ̀ eléwé kì í sì í rọ , gbogbo nǹkan tí ó bá ń ṣe ni yóò sì máa kẹ́sẹ járí . ” — Sáàmù 1 : 3 . | Bibeli so pe eeyan to ba n gbe iru igbe aye bee , a " da bi igi ti a gbin sebaa awon isan omi , ti n pese eso tire ni asiko re eyi ti awon eka re elewe ki i si i ro , gbogbo nnkan ti o ba n se ni yoo si maa kese jari . " -- Saamu 1 : 3 . |
Lórí pẹ̀tẹ́lẹ̀ ti Móábù pẹ̀lú Jọ́dánì tí ó kọjá Jẹ́ríkò, Mósè àti Élíásárì àlùfáà sọ̀rọ̀ pẹ̀lú wọn ó wí pé, Ka iye àwọn ọkùnrin tí ó jẹ́ ọmọ ogun ọdún tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ, gẹ́gẹ́ bí Olúwa ti paláṣẹ fún Mósè | Lori petele ti Moabu pelu Jodani ti o koja Jeriko, Mose ati Eliasari alufaa soro pelu won o wi pe, Ka iye awon okunrin ti o je omo ogun odun tabi ju bee lo, gege bi Oluwa ti palase fun Mose |
Gẹ́gẹ́ bí kìnnìún yóò fi ibùba rẹ̀ sílẹ̀, ilẹ̀ wọn yóò sì di ahoro, nítorí idà àwọn anínilára, àti nítorí ìbínú ńlá Olúwa | Gege bi kinniun yoo fi ibuba re sile, ile won yoo si di ahoro, nitori ida awon aninilara, ati nitori ibinu nla Oluwa |
Bí ẹ bá ti gbọ́ ìbáwí ì mi ni, Ǹ bá ti tú ohun tí ó wà nínú ọkàn mi jáde fún yín kí n sì fi inú un mi hàn sí i yín | Bi e ba ti gbo ibawi i mi ni, N ba ti tu ohun ti o wa ninu okan mi jade fun yin ki n si fi inu un mi han si i yin |
Tá a bá ń ṣe bẹ́ẹ̀ , Jèhófà máa rí sí i pé ọwọ́ wa tẹ àwọn nǹkan tá a ṣaláìní . | Ta a ba n se bee , Jehofa maa ri si i pe owo wa te awon nnkan ta a salaini . |
Àmọ́ , Jésù ò rí wọn bí ìdíwọ́ . | Amo , Jesu o ri won bi idiwo . |
Nígbà tó yá , àwọn ọmọ ẹ̀yìn Calvin gbé ọ̀kan lára ẹ̀kọ́ wọn tó ń fa àríyànjiyàn jù lọ jáde , ìyẹn àyànmọ́ . | Nigba to ya , awon omo eyin Calvin gbe okan lara eko won to n fa ariyanjiyan ju lo jade , iyen ayanmo . |
Kí Nìdí Tí Ohun Tí Mátíù àti Lúùkù Sọ Nípa Ìgbà Tí Jésù Wà Ní Kékeré Fi Yàtọ̀ Síra ? Aug . | Ki Nidi Ti Ohun Ti Matiu ati Luuku So Nipa Igba Ti Jesu Wa Ni Kekere Fi Yato Sira ? Aug . |
Ká tó lè “ sá fún àgbèrè , ” a gbọ́dọ̀ yẹra fún gbogbo ohun tó jẹ́ mọ́ ìwà àìmọ́ takọtabo àti ìwà àìníjàánu tó lè súnni dórí dídá ẹ̀ṣẹ̀ por·neiʹa tó burú jáì . | Ka to le “ sa fun agbere , ” a gbodo yera fun gbogbo ohun to je mo iwa aimo takotabo ati iwa ainijaanu to le sunni dori dida ese por·neiʹa to buru jai . |
Jésù sì kìlọ̀ fún wọn gidigidi pé kí wọn má ṣe sọ ohun tí ó ti ṣẹlẹ̀ | Jesu si kilo fun won gidigidi pe ki won ma se so ohun ti o ti sele |
Ìran yìí ń tọ́ka sí Ìjọba Ọlọ́run , nígbà tí Jésù àtàwọn tó jíǹde látinú ayé á máa ṣàkóso , tí wọ́n á sì fòpin sí ìṣàkóso Sátánì . | Iran yii n toka si Ijoba Olorun , nigba ti Jesu atawon to jinde latinu aye a maa sakoso , ti won a si fopin si isakoso Satani . |
Ó tiẹ̀ wó àga mọ́ akẹ́kọ̀ọ́ ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ nígbà kan , ó sì fi pẹ́ńsù gún akẹ́kọ̀ọ́ mìíràn . | O tie wo aga mo akekoo elegbe re nigba kan , o si fi pensu gun akekoo miiran . |
Yára láti ràn mí lọ́wọ́,, Olùgbàlà mi. | Yara lati ran mi lowo,, Olugbala mi. |
Jerusalẹmu, Lẹ́yìn Ìṣubú Rẹ̀. | Jerusalemu, Leyin Isubu Re. |
Lẹ́yìn ọ̀sẹ̀ méjì tá a lò nínú ọkọ̀ ojú irin , a dé ìlú Asino ní àgbègbè Tomsk , wọ́n sì dà wá sílẹ̀ níbẹ̀ bí màlúù . | Leyin ose meji ta a lo ninu oko oju irin , a de ilu Asino ni agbegbe Tomsk , won si da wa sile nibe bi maluu . |
Bí ọ̀gá ilé iṣẹ́ kan bá sì sọ fún ọ pé àwọn ò ní iṣẹ́ táwọn lè fún ọ ṣe , bi í léèrè bóyá ó mọ ibòmíì tó o lè wáṣẹ́ sí àtẹni tó o lè kàn sí . | Bi oga ile ise kan ba si so fun o pe awon o ni ise tawon le fun o se , bi i leere boya o mo ibomii to o le wase si ateni to o le kan si . |
Lẹ́yìn náà , “ Bárákì sì bẹ̀rẹ̀ sí sọ̀ kalẹ̀ láti orí Òkè Ńlá Tábórì pẹ̀lú ẹgbẹ̀rún mẹ́wàá ọkùnrin lẹ́yìn rẹ̀ . ” — Àwọn Onídàájọ́ 4 : 14 . | Leyin naa , " Baraki si bere si so kale lati ori Oke Nla Tabori pelu egberun mewaa okunrin leyin re . " -- Awon Onidaajo 4 : 14 . |
Kristi ti rà wá padà kúrò lọ́wọ́ ègún òfin, ẹni tí a fi ṣe ègún fún wa: nítorí tí a ti kọ ọ́ pé, “Ìfibú ni olúkúlùkù ẹni tí a fi kọ́ sórí igi.” | Kristi ti ra wa pada kuro lowo egun ofin, eni ti a fi se egun fun wa: nitori ti a ti ko o pe, "Ifibu ni olukuluku eni ti a fi ko sori igi." |
Iṣẹ́ Àwọn Ọmọ Lefi–Ìdílé Kohati. | Ise Awon Omo Lefi-Idile Kohati. |
Nítorí náà , ní ẹ̀wádún tó kọjá , gbogbo Àkájọ Ìwé Òkun Òkú ló ti wà lárọ̀ọ́wọ́tó fún àyẹ̀wò . | Nitori naa , ni ewadun to koja , gbogbo Akajo Iwe Okun Oku lo ti wa laroowoto fun ayewo . |
Ohun tó yẹ kó o fi sọ́kàn : Àkókò tá a wà yìí ló ṣe pàtàkì jù lọ pé káwọn òbí ran àwọn ọmọ wọn lọ́wọ́ láti “ kọ́ agbára ìwòye wọn ” kí wọ́n lè máa “ fi ìyàtọ̀ sáàárín ohun tí ó tọ́ àti ohun tí kò tọ́ . ” — Hébérù 5 : 14 . | Ohun to ye ko o fi sokan : Akoko ta a wa yii lo se pataki ju lo pe kawon obi ran awon omo won lowo lati “ ko agbara iwoye won ” ki won le maa “ fi iyato saaarin ohun ti o to ati ohun ti ko to . ” — Heberu 5 : 14 . |
Bẹ́ẹ̀ ni , bá a ṣe ń ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Ilé Ìṣọ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ , ńṣe ni à ń “ làdí ” Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tá a sì “ ń fi ìtumọ̀ sí i ” bí wọ́n ti ṣe nígbà ayé Nehemáyà . — Neh . | Bee ni , ba a se n se Ikekoo Ile Iso losoose , nse ni a n " ladi " Oro Olorun ta a si " n fi itumo si i " bi won ti se nigba aye Nehemaya . -- Neh . |
Nígbà míì sì rèé , gbogbo àwọn tí wọ́n jọ ń sọ èdè kan náà kì í ju àwọn tí wọ́n kàn jọ ń gbé ní àwọn abúlé kéékèèké mélòó kan lọ . | Nigba mii si ree , gbogbo awon ti won jo n so ede kan naa ki i ju awon ti won kan jo n gbe ni awon abule keekeeke meloo kan lo . |
Ìwé Òwe 24 : 10 sọ pé : “ Ìwọ ha ti jẹ́ kí ìrẹ̀wẹ̀sì bá ọ ní ọjọ́ wàhálà bí ? | Iwe Owe 24 : 10 so pe : “ Iwo ha ti je ki irewesi ba o ni ojo wahala bi ? |
Nígbà tó o bá wà nínú ìpọ́njú , ìwọ́ náà lè lo ìdánúṣe láti yanjú ìṣòro rẹ . | Nigba to o ba wa ninu iponju , iwo naa le lo idanuse lati yanju isoro re . |
( a ) Kí ni olórí ohun tó ń mú wa tọ́jú àwọn òbí wa àgbàlagbà ? | ( a ) Ki ni olori ohun to n mu wa toju awon obi wa agbalagba ? |
Nuuh àti (iran) 'Aad àti Fir'aona, | Nuuh ati (iran) 'Aad ati Fir'aona, |
Nínú ọ̀rọ̀ yìí , àwọn òbí ẹ ló wà nípò àṣẹ . | Ninu oro yii , awon obi e lo wa nipo ase . |
Kó o tó fẹsẹ̀ lé ọ̀nà kan , kọ́kọ́ bi ara rẹ pé , ‘ Kí ló máa jẹ́ ìgbẹ̀yìn rẹ̀ ? ’ | Ko o to fese le ona kan , koko bi ara re pe , ' Ki lo maa je igbeyin re ? ' |