diacritcs
stringlengths 1
36.7k
| no_diacritcs
stringlengths 1
35.5k
|
---|---|
Wọn kò sì rántí Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó gbà wọ́n kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá wọn gbogbo tí ó wà ní gbogbo àyíká wọn. | Won ko si ranti Olorun won, eni ti o gba won kuro lowo awon ota won gbogbo ti o wa ni gbogbo ayika won. |
Yíká ayé , ọrẹ àtinúwá ni àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń lò láti fi kọ́ àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba , Gbọ̀ngàn Àpéjọ , ẹ̀ka ọ́fíìsì àtàwọn ilé ìtẹ̀wé wọn , ọrẹ àtinúwá yìí náà ni wọ́n sì ń lò láti fi ṣèrànwọ́ fún àwọn tí àjálù dé bá . | Yika aye , ore atinuwa ni awon Elerii Jehofa n lo lati fi ko awon Gbongan Ijoba , Gbongan Apejo , eka ofiisi atawon ile itewe won , ore atinuwa yii naa ni won si n lo lati fi seranwo fun awon ti ajalu de ba . |
Jóòbù kì í ṣe èèyànkéèyàn tàbí òǹrorò ẹ̀dá . | Joobu ki i se eeyankeeyan tabi onroro eda . |
Ẹni tí ó ti búra fún ,tí ó sì ṣe ìlérí fún Alágbára Jakọbu pé. | Eni ti o ti bura fun ,ti o si se ileri fun Alagbara Jakobu pe. |
Ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ èyíkéyí nínú òkú ẹranko náà gbọdọ̀ fọ aṣọ rẹ̀, yóò sì di aláìmọ́ títí ìrọ̀lẹ́ | Enikeni ti o ba je eyikeyi ninu oku eranko naa gbodo fo aso re, yoo si di alaimo titi irole |
Kí Ló Máa Ń Ṣẹlẹ̀ sí Ìrònú Ẹni Tó Bá Ti Kú ? | Ki Lo Maa N Sele si Ironu Eni To Ba Ti Ku ? |
Ẹ máa ronú nípa àwọn tó wà ní ìpínlẹ̀ ìwàásù yín àti ohun tó máa mú kí wọ́n fẹ́ tẹ́tí sí ọ̀rọ̀ yín . | E maa ronu nipa awon to wa ni ipinle iwaasu yin ati ohun to maa mu ki won fe teti si oro yin . |
Èyí ni ohun tí Olúwa sọ | Eyi ni ohun ti Oluwa so |
Ọmọ afẹ̀jẹ̀ ẹlẹ́jẹ̀ wẹ̀ | Omo afeje eleje we |
Ó mú kí àjọṣe rẹ̀ pẹ̀lú Ọlọ́run túbọ̀ dán mọ́rán sí i . | O mu ki ajose re pelu Olorun tubo dan moran si i . |
Bí àpẹẹrẹ , ọkùnrin kan tó ní àrùn ẹ̀tẹ̀ wá sọ́dọ̀ Jésù , ó sì bẹ̀ ẹ́ pé : “ Bí ìwọ bá sáà ti fẹ́ bẹ́ẹ̀ , ìwọ lè mú kí èmi mọ́ . ” | Bi apeere , okunrin kan to ni arun ete wa sodo Jesu , o si be e pe : " Bi iwo ba saa ti fe bee , iwo le mu ki emi mo . " |
Tó bá rí bẹ́ẹ̀ , ẹ jẹ́ ká ‘ ra oògùn ojú lọ́dọ̀ Jésù ’ ká lè rí bó ti ṣe pàtàkì tó láti fi ìtara wá Ìjọba náà lákọ̀ọ́kọ́ . — Mátíù 6 : 33 . | To ba ri bee , e je ka ‘ ra oogun oju lodo Jesu ’ ka le ri bo ti se pataki to lati fi itara wa Ijoba naa lakooko . — Matiu 6 : 33 . |
Àmọ́ , Isaac Comnenus ní kí wọ́n mú un , wọ́n jù ú sẹ́wọ̀n , wọ́n sì lé e lọ sí erékùṣù Imbros . | Amo , Isaac Comnenus ni ki won mu un , won ju u sewon , won si le e lo si erekusu Imbros . |
“ Alátakò ” ni ìtumọ̀ ọ̀rọ̀ náà , “ Sátánì . ” | “ Alatako ” ni itumo oro naa , “ Satani . ” |
ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 3 OJÚ ÌWÉ 20 sí 24 | APILEKO FUN IKEKOO 3 OJU IWE 20 si 24 |
Mo gbádùn oṣù yẹn gan - an débi pé lọ́dún 1996 , mo di aṣáájú - ọ̀nà déédéé , ìyẹn òjíṣẹ́ Ọlọ́run tó ń lo àádọ́rùn - ún [ 90 ] wákàtí lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù lóṣooṣù . | Mo gbadun osu yen gan - an debi pe lodun 1996 , mo di asaaju - ona deedee , iyen ojise Olorun to n lo aadorun - un [ 90 ] wakati lenu ise iwaasu losoosu . |
Òótọ́ ni pé kì í ṣe gbogbo ọkọ , aya , àwọn ọmọ , àwọn òbí tàbí àwọn mọ̀lẹ́bí tó jẹ́ aláìgbàgbọ́ ló máa ń wá sínú ìjọsìn tòótọ́ , kódà lẹ́yìn ọ̀pọ̀ ọdún tí ẹni tó jẹ́ Ẹlẹ́rìí ti ń hùwà tó dáa , tó sì ti ń fi ọgbọ́n wàásù fún wọn . | Ooto ni pe ki i se gbogbo oko , aya , awon omo , awon obi tabi awon molebi to je alaigbagbo lo maa n wa sinu ijosin tooto , koda leyin opo odun ti eni to je Elerii ti n huwa to daa , to si ti n fi ogbon waasu fun won . |
Èyí ló mú kí Pọ́ọ̀lù tún èrò pa tó sì kọ lẹ́tà tá a wá mọ̀ sí Kọ́ríńtì Kìíní . | Eyi lo mu ki Poolu tun ero pa to si ko leta ta a wa mo si Korinti Kiini . |
Bí wọ́n bá tiẹ̀ ti gba kámú tẹ́lẹ̀ , ó máa ń mú kí wọ́n fẹ́ láti ṣe nǹkan kan kí wọ́n lè yanjú ìṣòro náà . | Bi won ba tie ti gba kamu tele , o maa n mu ki won fe lati se nnkan kan ki won le yanju isoro naa . |
Ọré mi keji Abdullai Awòlúmátẹ̀€, ẹni tí orúkọ rẹ̀ n pòwe kì í | Ore mi keji Abdullai Awolumate€, eni ti oruko re n powe ki i |
Ìjọba ọ̀run tí Ẹlẹ́dàá ìran ènìyàn , Jèhófà Ọlọ́run dá sílẹ̀ , èyí tí Jésù Kristi yòó máa ṣàkóso bí Ọba rẹ̀ ni yóò mú àyípadà yìí wá . | Ijoba orun ti Eledaa iran eniyan , Jehofa Olorun da sile , eyi ti Jesu Kristi yoo maa sakoso bi Oba re ni yoo mu ayipada yii wa . |
nínú rẹ̀ àti pé kí ọkàn wa lẹ̀ balẹ̀, kí | ninu re ati pe ki okan wa le bale, ki |
Ẹ máa kíyèsi àṣẹ mi, kí ẹ sì máa pa wọ́n mọ́: Èmi ni tí ó sọ yín di mímọ́. | E maa kiyesi ase mi, ki e si maa pa won mo: Emi ni ti o so yin di mimo. |
Lọ́dún 1823 , ṣàdédé ni akọ̀wé kan rí ìwé gbajúmọ̀ òǹkọ̀wé ewì yìí , níbi tí wọ́n fi bébà wé e pa mọ́ sí . | Lodun 1823 , sadede ni akowe kan ri iwe gbajumo onkowe ewi yii , nibi ti won fi beba we e pa mo si . |
Òpìtàn Carolly Erickson ṣàpèjúwe bí wọ́n ṣe ń sun wọ́n , ó wí pé : “ Lọ́pọ̀ ìgbà , igi tútù ni wọ́n fi máa ń dá iná náà , tàbí kí wọ́n lo koríko tútù tí kò ní tètè jó . | Opitan Carolly Erickson sapejuwe bi won se n sun won , o wi pe : " Lopo igba , igi tutu ni won fi maa n da ina naa , tabi ki won lo koriko tutu ti ko ni tete jo . |
( Wo ìpínrọ̀ 17 ) | ( Wo ipinro 17 ) |
Lákọ̀ọ́kọ́ ná , Ọlọ́run sọ fún wa léraléra pé òun fẹ́ ràn wá lọ́wọ́ . | Lakooko na , Olorun so fun wa leralera pe oun fe ran wa lowo . |
Àwọn ọ̀rọ̀ kan wà tí àwọn ènìyàn sọ ní orú yìí tí ó yẹ kí á ṣe àkíyèsí. | Awon oro kan wa ti awon eniyan so ni oru yii ti o ye ki a se akiyesi. |
Bí ẹnikẹ́ni bá lóun gbójú gbóyà tó lọ kọlu àwọn yòókù tó máa di ara Ìjọba náà , ńṣe lonítọ̀hún ń fẹsẹ̀ wọnsẹ̀ pẹ̀lú Ìjọba Ọlọ́run . — Ìṣípayá 12 : 17 . | Bi enikeni ba loun gboju gboya to lo kolu awon yooku to maa di ara Ijoba naa , nse lonitohun n fese wonse pelu Ijoba Olorun . -- Isipaya 12 : 17 . |
Ní àkókò yẹn , ó ṣeé ṣe kí inú rẹ dùn pé bàbá ni ọ́ . | Ni akoko yen , o see se ki inu re dun pe baba ni o . |
Oníbàtá kì í wọ mọ́ṣáláṣí kó ní “Lèmámù ńkọ́?” | Onibata ki i wo mosalasi ko ni “Lemamu nko?” |
Lójú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà , kì í ṣe torí pé wọ́n kàn fẹ́ tan ẹ̀sìn kálẹ̀ ni wọ́n ṣe ń lọ láti ẹnu ọ̀nà dé ẹnu ọ̀nà láti yíni lọ́kàn pa dà , àmọ́ ṣe ni wọ́n gbà pe iṣẹ́ yẹn jẹ́ ọ̀nà pàtàkì téèyàn gbà ń fi hàn pé òun ní ìgbàgbọ́ . ” | Loju awon Elerii Jehofa , ki i se tori pe won kan fe tan esin kale ni won se n lo lati enu ona de enu ona lati yini lokan pa da , amo se ni won gba pe ise yen je ona pataki teeyan gba n fi han pe oun ni igbagbo . " |
Inú mi ń dùn láti máa ṣètìlẹ́yìn fún ọkọ mi bó ṣe ń ṣèrànwọ́ láti bójú tó ìjọ tí à ń dara pọ̀ mọ́ . | Inu mi n dun lati maa setileyin fun oko mi bo se n seranwo lati boju to ijo ti a n dara po mo . |
Nítorí náà , a ń fi ìdánilójú sọ pé : “ Bí Ọlọ́run bá wà fún wa , ta ni yóò wà lòdì sí wa ? ” — Róòmù 8 : 31 . | Nitori naa , a n fi idaniloju so pe : “ Bi Olorun ba wa fun wa , ta ni yoo wa lodi si wa ? ” — Roomu 8 : 31 . |
Fífọ́ ejò ní orí kan jíju Sátánì sínú ọ̀gbun àìnísàlẹ̀ nígbà Ẹgbẹ̀rún Ọdún Ìjọba Kristi . | Fifo ejo ni ori kan jiju Satani sinu ogbun ainisale nigba Egberun Odun Ijoba Kristi . |
Mi ò jẹ́ kóyán ẹ̀ kéré , ọ̀pọ̀ ìgbà ni mo máa ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Jèhófà lóòjọ́ pó jẹ́ kí n bí ọmọ náà . ” | Mi o je koyan e kere , opo igba ni mo maa n dupe lowo Jehofa loojo po je ki n bi omo naa . ” |
Gẹ́gẹ́ bí ohun tí Bíbélì sọ , báwo ni Jèhófà ṣe pèsè ìrànwọ́ nípasẹ̀ àwọn onígbàgbọ́ ẹlẹgbẹ́ ẹni ? | Gege bi ohun ti Bibeli so , bawo ni Jehofa se pese iranwo nipase awon onigbagbo elegbe eni ? |
Tá a bá fẹ́ wà lára “ agbo kan , ” tá a sì fẹ́ máa tẹ̀ lé “ olùṣọ́ àgùntàn kan , ” àfi ká máa wá sípàdé déédéé . | Ta a ba fe wa lara " agbo kan , " ta a si fe maa te le " oluso aguntan kan , " afi ka maa wa sipade deedee . |
Ọlọ́rùn títóbi àti alágbára, Olúwa àwọn ọmọ-ogun ni orúkọ rẹ | Olorun titobi ati alagbara, Oluwa awon omo-ogun ni oruko re |
Ògo OLUWA gbéra kúrò láàrin ìlú náà, ó sì dúró sórí òkè tí ó wà ní apá ìhà ìlà oòrùn ìlú náà. | Ogo OLUWA gbera kuro laarin ilu naa, o si duro sori oke ti o wa ni apa iha ila oorun ilu naa. |
Nígbà yẹn , Ábúráhámù kò lóye ohun tí májẹ̀mú náà máa túmọ̀ sí fún aráyé délẹ̀délẹ̀ . | Nigba yen , Aburahamu ko loye ohun ti majemu naa maa tumo si fun araye deledele . |
Ó ṣe tán , àwa Kristẹni gbọ́dọ̀ jẹ́ olóòótọ́ . | O se tan , awa Kristeni gbodo je oloooto . |
Lipoftsoff túmọ̀ . | Lipoftsoff tumo . |
Kódà , láàárín àwọn Kristẹni tó ń gbé lápá ibì kan náà , ohun tó máa ń gbádùn mọ́ ẹnì kan ( bóyá kíka ìwé aládùn ) , lè máa sú ẹlòmíì ; ohun tó ń tu ẹnì kan lára ( bóyá kó máa gun kẹ̀kẹ́ najú káàkiri ) , lè jẹ́ ohun tó máa ń mú kó rẹ ẹlòmíì . | Koda , laaarin awon Kristeni to n gbe lapa ibi kan naa , ohun to maa n gbadun mo eni kan ( boya kika iwe aladun ) , le maa su elomii ; ohun to n tu eni kan lara ( boya ko maa gun keke naju kaakiri ) , le je ohun to maa n mu ko re elomii . |
O lọ si Ile-ẹkọ Gẹẹsi Geneva ati lẹhinna Ile-ẹkọ Alakọbẹrẹ Home Science, Ikoyi, fun eto-ẹkọ ti o kọkọ. | O lo si Ile-eko Geesi Geneva ati lehinna Ile-eko Alakobere Home Science, Ikoyi, fun eto-eko ti o koko. |
Ó wá pọn dandan káwa èèyàn ẹlẹ́ṣẹ̀ rí ọ̀nà láti pa dà bá Jèhófà rẹ́ . | O wa pon dandan kawa eeyan elese ri ona lati pa da ba Jehofa re . |
Ọ̀ṣọ́ọ́rọ́ obìnrin kan wà ní Íńdíà tó nílò ìtùnú lójú méjèèjì . | Osooro obinrin kan wa ni India to nilo itunu loju mejeeji . |
aṣíiwájú wọn ṣe n gbààyẹ̀. Báyìí | asiiwaju won se n gbaaye. Bayii |
Ronald Morrish , tó jẹ́ ògbógi nínú ọ̀ràn ìhùwà , sọ pé : “ Bí àwọn ọmọ bá mọ ààlà wọn , ó máa ń jẹ́ kí wọ́n rí ìdí tó fi yẹ kí wọ́n mọ ohun tí wọ́n ní láti retí àti ààbò wọn — tí yóò wá ràn wọ́n lọ́wọ́ láti ní iyì tó túbọ̀ pọ̀ . | Ronald Morrish , to je ogbogi ninu oran ihuwa , so pe : " Bi awon omo ba mo aala won , o maa n je ki won ri idi to fi ye ki won mo ohun ti won ni lati reti ati aabo won -- ti yoo wa ran won lowo lati ni iyi to tubo po . |
7. Àti pé báyìí ni Olúwa rẹ̀ yôò | 7. Ati pe bayii ni Oluwa re yoo |
Wọ́n fi bíbá àwọn aládùúgbò wọn sọ̀rọ̀ lọ́nà tó yááyì kún iṣẹ́ òjíṣẹ́ wọn . | Won fi biba awon aladuugbo won soro lona to yaayi kun ise ojise won . |
( b ) Kí ló fi hàn pé Ámósì kì í ṣe púrúǹtù ? | ( b ) Ki lo fi han pe Amosi ki i se puruntu ? |
A KÒ gbọ́dọ̀ jiyàn rẹ̀ pé iṣẹ́ tí wọ́n pè ní “ iṣẹ́ tó dára jù lọ ” yìí ń kojú onírúurú ìṣòro . | A KO gbodo jiyan re pe ise ti won pe ni “ ise to dara ju lo ” yii n koju oniruuru isoro . |
Ní oṣù karùn-ún ọdún keje ọba yìí ni Esra dé sí Jerusalẹmu. | Ni osu karun-un odun keje oba yii ni Esra de si Jerusalemu. |
49. Àwa sì ti sọ Ìwé náà tí òô kún | 49. Awa si ti so Iwe naa ti oo kun |
Ní wákàtí kan náà, díẹ̀ nínú àwọn Farisi tọ̀ ọ́ wá, wọ́n sì wí fún un pé, “Jáde, kí ìwọ sì lọ kúrò níhìn-ín yìí: nítorí Herodu ń fẹ́ pa ọ́.” | Ni wakati kan naa, die ninu awon Farisi to o wa, won si wi fun un pe, "Jade, ki iwo si lo kuro nihin-in yii: nitori Herodu n fe pa o." |
Korobá kan tí kò ní ìdérí ni ilé ìgbọ̀nsẹ̀ tó wà níbi tí wọ́n tì mí mọ́ . | Koroba kan ti ko ni ideri ni ile igbonse to wa nibi ti won ti mi mo . |
Kíyèsí i, èmí ti dúró de ọ̀rọ̀ yín | Kiyesi i, emi ti duro de oro yin |
Níkẹyìn , a dé New York , níbi tá a ti ṣe àpéjọ náà . | Nikeyin , a de New York , nibi ta a ti se apejo naa . |
elúsáì | elusai |
Ṣùgbọ́n, èmi yóò mú Israẹlipadà wá pápá oko tútù rẹ̀òun yóò sì máa bọ́ ara rẹ̀ lórí Karmeli àti Baṣani,a ó sì tẹ́ ọkàn rẹ̀ lọ́rùn ní òkèEfraimu àti ní Gileadi | Sugbon, emi yoo mu Israelipada wa papa oko tutu reoun yoo si maa bo ara re lori Karmeli ati Basani,a o si te okan re lorun ni okeEfraimu ati ni Gileadi |
Ṣe ni wọ́n gbà pé ó máa bu Ọlọ́run kù tí a bá sọ pé ó jẹ́ ọkàn , torí ọ̀rọ̀ yẹn ni Bíbélì máa ń lò fún àwọn ẹ̀dá abẹ̀mí inú ayé . | Se ni won gba pe o maa bu Olorun ku ti a ba so pe o je okan , tori oro yen ni Bibeli maa n lo fun awon eda abemi inu aye . |
Wọ́n torí ajá ńlóṣòó lọ fowó rọ̀bọ. | Won tori aja nlosoo lo fowo robo. |
Nígbà tí òpìtàn Augustus Neander ń sọ̀rọ̀ nípa àwọn Kristẹni ọ̀rúndún kìíní , ohun tó kọ sínú ìwé rẹ̀ tó dá lórí ìsìn Kristẹni ni pé : “ Kìkì àwọn tó dàgbà ló máa ń ṣe ìrìbọmi níbẹ̀rẹ̀ , nítorí pé àwọn èèyàn gbà pé kò sẹ́ni tó lè ṣèrìbọmi láìní ìgbàgbọ́ . ” — Ìwé General History of the Christian Religion and Church . | Nigba ti opitan Augustus Neander n soro nipa awon Kristeni orundun kiini , ohun to ko sinu iwe re to da lori isin Kristeni ni pe : “ Kiki awon to dagba lo maa n se iribomi nibere , nitori pe awon eeyan gba pe ko seni to le seribomi laini igbagbo . ” — Iwe General History of the Christian Religion and Church . |
Nígbà tó lọ lo àkókò ìsinmi lórílẹ̀ - èdè Cambodia , ọmọbìnrin kan wá tọrọ owó lọ́wọ́ rẹ̀ nígbà tó ń jẹun lọ́wọ́ nílé oúnjẹ kan nílùú Phnom Penh . | Nigba to lo lo akoko isinmi lorile - ede Cambodia , omobinrin kan wa toro owo lowo re nigba to n jeun lowo nile ounje kan niluu Phnom Penh . |
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé | Ibeere Lati Owo Awon Onkawe |
Máa gbẹ́sẹ̀ lọ́kọ̀ọ̀kan , ní ṣísẹ̀ - n - tẹ̀lé , láìkánjú . | Maa gbese lokookan , ni sise - n - tele , laikanju . |
Ó wá fi kún un pé : “ Dẹ etí rẹ sí ìfòyemọ̀ mi , kí o bàa lè ṣọ́ agbára láti ronú ; kí ètè tìrẹ sì fi ìṣọ́ ṣọ́ ìmọ̀ . ” — Òwe 5 : 1 , 2 . | O wa fi kun un pe : " De eti re si ifoyemo mi , ki o baa le so agbara lati ronu ; ki ete tire si fi iso so imo . " -- Owe 5 : 1 , 2 . |
Lóòótọ́ , iṣẹ́ àwọn alàgbà pọ̀ gan - an . | Loooto , ise awon alagba po gan - an . |
Kí ló ti jẹ́ àbájáde ìbínú òdì tó ń tàn kálẹ̀ yìí ? | Ki lo ti je abajade ibinu odi to n tan kale yii ? |
Ilu naa ni awọn cul-de-sacs tabi awọn pipade eyiti o jẹ orukọ ni ọna kika alfabeti kan. | Ilu naa ni awon cul-de-sacs tabi awon pipade eyiti o je oruko ni ona kika alfabeti kan. |
Ǹjẹ́ O Mọ Ṣáfánì àti Ìdílé Rẹ̀ ? | Nje O Mo Safani ati Idile Re ? |
Àníyàn tí ọba yìí ń ṣe nípa bí ẹ̀sìn Pùròtẹ́sítáǹtì ṣe tàn kálẹ̀ ló mú kó ṣèwádìí nípa àwọn tí wọ́n pè ní aládàámọ̀ nínú ìjọba rẹ̀ . | Aniyan ti oba yii n se nipa bi esin Purotesitanti se tan kale lo mu ko sewadii nipa awon ti won pe ni aladaamo ninu ijoba re . |
Ó jẹ́ pé lítíréṣọ̀ ni ọ̀rọ̀ tàbí èdè ọgbọ́n tí a fi ohun gbé jáde ni àwùjọ sọ̀rọ̀ sọ̀rọ̀ kí ó tó di kíkọ́ sílẹ̀ nípa ìlànà mọ̀ọ́kọmọ̀ọ́kà ní àwùjọ alákọ̀wé Èrò yìí tẹ̀síwàjú nígbà tí Babalọlá sọ pé lítíréṣọ̀ ni ìlànà tí à ń gbà sọ fún ayé gbọ́ ohun tí ó jẹ ni lọ́kàn nípa àyíká Èyí tí a gbé kalẹ̀ lọ́nà tààrà tàbí lọ́nà àlùmọ̀kọ́rọ́yí lọ́pọ̀ ìgbà láì dárúkọ pàtó àwọn ẹní ti ọ̀rọ̀ kàn ganan Ṣùgbọ́n tí àṣàyàn ọ̀rọ̀ ìjìnlẹ̀ pẹ̀lú ohun tó fẹ́wa fún ohun tí à ń sọ náà ń ṣáábà jẹ ẹní tí ń ṣe àgbékalẹ̀ lógún | O je pe litireso ni oro tabi ede ogbon ti a fi ohun gbe jade ni awujo soro soro ki o to di kiko sile nipa ilana mookomooka ni awujo alakowe Ero yii tesiwaju nigba ti Babalola so pe litireso ni ilana ti a n gba so fun aye gbo ohun ti o je ni lokan nipa ayika Eyi ti a gbe kale lona taara tabi lona alumokoroyi lopo igba lai daruko pato awon eni ti oro kan ganan Sugbon ti asayan oro ijinle pelu ohun to fewa fun ohun ti a n so naa n saaba je eni ti n se agbekale logun |
bátànìi | batanii |
Ṣugbọn mo ní nǹkan wí sí ọ. O ti kọ ìfẹ́ tí o ní nígbà tí o kọ́kọ́ gbàgbọ́ sílẹ̀. | Sugbon mo ni nnkan wi si o. O ti ko ife ti o ni nigba ti o koko gbagbo sile. |
ṣe gbàgbé ìpin rẹ layé yìí, kí o sì | se gbagbe ipin re laye yii, ki o si |
Àwa Kristẹni ‘ ní gídígbò kan lòdì sí àwọn agbo ọmọ ogun ẹ̀mí burúkú ’ | Awa Kristeni ‘ ni gidigbo kan lodi si awon agbo omo ogun emi buruku ’ |
Town in Lagos State, NigeriaÀdàkọ:SHORTDESC:Town in Lagos State, Nigeria Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6°27′47″N 3°23′15″E / 6.46306°N 3.38750°E / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) | Town in Lagos State, NigeriaAdako:SHORTDESC:Town in Lagos State, Nigeria Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) Ebute Ero Town Ebute-Ero street, showing Tram" Lines (between 1910 and 1913) Ebute Ero Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750Coordinates: 6deg27'47''N 3deg23'15''E / 6.46306degN 3.38750degE / 6.46306; 3.38750 Country Nigeria State Lagos State Time zone UTC+1 (WAT) |
Wọn ò di ojúlùmọ̀ ọ̀rọ̀ náà nípa jíjẹ́ kó máa darí wọn láti ṣe ìpinnu tó mọ́gbọ́n dáni nígbèésí ayé wọn . | Won o di ojulumo oro naa nipa jije ko maa dari won lati se ipinnu to mogbon dani nigbeesi aye won . |
1 , 2 . ( a ) Àǹfààní wo ni Jésù gbé lé àpọ́sítélì Pétérù lọ́wọ́ , kí ló sì fi hàn pé kò sóun tó burú nínú bí Jésù ṣe fọkàn tán Pétérù ? | 1 , 2 . ( a ) Anfaani wo ni Jesu gbe le apositeli Peteru lowo , ki lo si fi han pe ko soun to buru ninu bi Jesu se fokan tan Peteru ? |
Bẹ́ẹ̀ sì rèé , ará Gálílì ni àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù tó ń bá wọn sọ̀rọ̀ . | Bee si ree , ara Galili ni awon omo eyin Jesu to n ba won soro . |
Àwọn Kristẹni pàápàá ka bíbọ̀wọ̀ fún àwọn òbí àti nínífẹ̀ẹ́ wọn sí ohun pàtàkì . | Awon Kristeni paapaa ka bibowo fun awon obi ati ninifee won si ohun pataki . |
Ohun tí àwọn tó gbé fíìmù yìí jáde ṣe ni pé wọ́n gbé kámẹ́rà aláfọwọ́yí kan sí iwájú ọkọ̀ kan tó ń rìn lára okùn irin tí wọ́n ta sára àwọn òpó gíga . | Ohun ti awon to gbe fiimu yii jade se ni pe won gbe kamera alafowoyi kan si iwaju oko kan to n rin lara okun irin ti won ta sara awon opo giga . |
( b ) Báwo làwọn “ àgùntàn mìíràn ” ṣe ń ran àwọn ẹni àmì òróró yìí lọ́wọ́ ? | ( b ) Bawo lawon “ aguntan miiran ” se n ran awon eni ami ororo yii lowo ? |
Lára ohun tí Ọlọ́run ń pèsè fún wa ni “ ìtùnú ẹ̀mí mímọ́ . ” | Lara ohun ti Olorun n pese fun wa ni " itunu emi mimo . " |
Àbí ẹ ò rí i pé Jèhófà fẹ́ràn láti máa dá àwọn èèyàn rẹ̀ lẹ́kọ̀ọ́ ! | Abi e o ri i pe Jehofa feran lati maa da awon eeyan re lekoo ! |
Bóyá la fi rí ẹnì kan tí kò da omi lójú nínú wọn . | Boya la fi ri eni kan ti ko da omi loju ninu won . |
Tún gbìyànjú láti wo ọ̀ràn náà bí Jehófà ṣe wò ó . | Tun gbiyanju lati wo oran naa bi Jehofa se wo o . |
Ọkọ kan tó ń jẹ́ Carlos sọ pé : “ Inú àwa ọkùnrin máa ń dùn tá a bá rí i pé a lè bójú tó ìdílé wa , ká sì yanjú ìṣòro . ” | Oko kan to n je Carlos so pe : “ Inu awa okunrin maa n dun ta a ba ri i pe a le boju to idile wa , ka si yanju isoro . ” |
Báwo lo ṣe máa kọ́ ọmọ rẹ tí kò tíì pé ogún ọdún nípa irú ìbálòpọ̀ tí ó tọ́ ? | Bawo lo se maa ko omo re ti ko tii pe ogun odun nipa iru ibalopo ti o to ? |
“Ọmọ ènìyàn, àwọn arákùnrin rẹ, àní àwọn ará rẹ, àwọn ọkùnrin nínú ìbátan rẹ, àti gbogbo ilé Israẹli pátápátá, ni àwọn ará Jerusalẹmu ti wí fún pé, ‘Ẹ jìnnà sí , àwa ni a fi ilẹ̀ yìí fún yín ní ìní.’ | “Omo eniyan, awon arakunrin re, ani awon ara re, awon okunrin ninu ibatan re, ati gbogbo ile Israeli patapata, ni awon ara Jerusalemu ti wi fun pe, ‘E jinna si , awa ni a fi ile yii fun yin ni ini.’ |
Peteru sì wí pé, “Nítorí a ti kọ ọ́ nípa rẹ̀ nínú Ìwé Saamu pé,“ ‘Jẹ́ ki ibùgbé rẹ̀ di ahoro,kí ẹnikẹ́ni má ṣe gbé inú rẹ̀,’àti,“ ‘Ipò rẹ̀ ni kí ẹlòmíràn kí ó gbà.’ | Peteru si wi pe, "Nitori a ti ko o nipa re ninu Iwe Saamu pe," 'Je ki ibugbe re di ahoro,ki enikeni ma se gbe inu re,'ati," 'Ipo re ni ki elomiran ki o gba.' |
Gbogbo ìgbà tó bá lọ kọ́ obìnrin náà lẹ́kọ̀ọ́ ló máa ń rí ọmọ náà tó ń fi ìbọn oníke kékeré kan ṣeré , ohun ìṣeré kan ṣoṣo tó sì ní nìyẹn . | Gbogbo igba to ba lo ko obinrin naa lekoo lo maa n ri omo naa to n fi ibon onike kekere kan sere , ohun isere kan soso to si ni niyen . |
Nítorí náà, ẹ gbé àánú wọ̀ bí ẹ̀wù, ati inú rere, ìrẹ̀lẹ̀, ìwà pẹ̀lẹ́ ati sùúrù, bí ó ti yẹ àwọn ẹni tí Ọlọrun yàn, tí wọ́n sì jẹ́ eniyan Ọlọrun ati àyànfẹ́ rẹ̀. | Nitori naa, e gbe aanu wo bi ewu, ati inu rere, irele, iwa pele ati suuru, bi o ti ye awon eni ti Olorun yan, ti won si je eniyan Olorun ati ayanfe re. |
Wọ́n ń fi sọ́kàn pé àwọn èèyàn lẹ́tọ̀ọ́ láti ṣe ẹ̀sìn tó bá wù wọ́n . | Won n fi sokan pe awon eeyan letoo lati se esin to ba wu won . |
Nítorí náà , á dáa kó o wáyè láti kíyè sí ẹnì kan dáadáa kó o lè rí i bóyá ìwà rẹ̀ bá ọ̀rọ̀ rẹ̀ mu . | Nitori naa , a daa ko o waye lati kiye si eni kan daadaa ko o le ri i boya iwa re ba oro re mu . |
Òun sì máa fì yan àwọn tí ô bá wù | Oun si maa fi yan awon ti o ba wu |
Àmọ́ ní báyìí , a ti rí i pé kò sí bí àwa nìkan ṣe lè máa dá ṣe gbogbo nǹkan . | Amo ni bayii , a ti ri i pe ko si bi awa nikan se le maa da se gbogbo nnkan . |
Ó dájú háún pé Jèhófà ló ń darí wọn . | O daju haun pe Jehofa lo n dari won . |